Ikilo Aye Eniayn Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1998
Lyrics
[ti:06 Ikilo Aye Eniyan]
Ijo mimo la wa wa
Ijo olore ofe nla
Lati owo jesu
Adura oshofa
Ile wunmi omo ojo mola
Oni kemi wa jowo
Oni kiwo wa jowo
Oba to wo tola ni
Aye wa ladun ju oyin lo
Oba lo ran wa wa o
Oba lo ran wa wa o
Oni ka tan imole
Sinu oknunkun araye
Karaye le ri imole
Ki won si le mo imole
Jesu kristi ni imole
Imole ti ki ku lai lai
Owa di ile baba mi
Abiodun bada baba re
Baba ke pe o
Baba ke pe o
Eni t’olorun mi pe
Lo ye larin opo to koko wa
To wa se logo
Logo ti koni baje lailai
E e ma gbe o ga baba orun o
Ma yin logo baba orun mimo
E e ma gbe o ga baba orun o
Ma yin logo baba orun mimo
Shoti l’olugbala
Moni
Shoti l’olugbala
Moni o
Shoti l’olugbala
Jesu l’olugbala mi
Shoti l’ala feyinti
Moni
Shoti l’ala feyinti
Moni o
Shoti l’ala feyinti
Jesu l’ala feyinti mi
Gbani gbani ti aye saya o
Gbani gbani gbani gbani gbani
Gbani gbani gban gbani gbani
Gbani gbani gban gbani gbani
Gbani gbani o
Gbani gbani ti aye nsaya o
Jesu mimo dakun wa gba mi o
Eledumare o
Oba tin dani lare o baba rere
Eledumare o
Oba tin segun o baba rere
Awa omo re ma re o
Awa mo eni ti a gbagbo
Toripe titobi ni o olorun ju awon oke lo o
Toripe gbigbe ga ni o olorun ju awon orun aye
Oba to fi idi aye sole sori okun
Alaragbayida o oba rere
Gbani gbani ti aye saya o
Gbani gbani gbani gbani gbani
Gbani gbani gban gbani gbani
Gbani gbani gban gbani gbani
Gbani gbani o
Gbani gbani ti aye nsaya o
Jesu mimo dakun wa gba mi o
E lalalalalalala o
Erupe ile won yin olorun
Eranko egbe won yin baba mi
Ewe ko igbe won yin olorun
Kawa so teniyan
Kawa so t’eda tada laworan olorun
A egbe ohun soke kajo yin baba
Tori mo mo mo
Tori mo mo mo
Tori mo mo mo
Tori mo mo mo
Tori moo
Tori moooo
Tori mo ni o ni baba moti se ori re
Tori mo ni o ni baba moti di asegun
Tori mo mo mo
Tori mo mo mo
Tori moo
Tori mo ni o ni baba moti se ori re
Tori mo ni o ni baba moti di asegun (x2)
E lalalalalalala o
Erupe ile won yin olorun
Eranko egbe won yin baba mi
Ewe ko igbe won yin olorun
Kawa so teniyan
Kawa so t’eda tada laworan olorun
A egbe ohun soke kajo yin baba
Tori mooo
Tori mo mo mo
Tori mo mo mo
Tori mo mo mo
Tori moo
Tori moooo
Tori mo ni o ni baba moti se ori re
Tori mo ni o ni baba moti di asegun
Tori mo ni o ni baba moti se ori re
Tori mo ni o ni baba moti di asegun
Tori mo ni o ni baba moti se ori re
Tori mo ni o ni baba moti di asegun
Tori mo ni o ni baba moti se ori re
Tori mo ni o ni baba moti di asegun