Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:1999

Lyrics

[ti:03 Emi Ni (I Am)]



Ara kunrin ma gbo

Ara binrin ma gbo

Oro olorun re o

Ko soun to shele laye ti ko shele ri

Afi ta o ba foro olorun k’ogbon

Gbogbo oun to shele laye ti ba wa leru

Oti shele si oluwa wa ri


Igbakigba t’ogun aye dide

Sha dake fi okan re bale

Ranti oltunu ni to so wipe


Emi ni mase beru omo

Omo mi ma gbo o

Emi ni mase beru omo

Omo mi ma gbo mi

Emi ni mase beru omo

Gbogbo ninu jesu

Emi ni mase beru omo


Be gege loro jesu lori omi

Be gege le oro jesu

Be gege loro olorun lori okun

Be gege le oro jesu

Emi ni mase beru omo


Iji yo de lojiji lori okun

Olugbala kosi ni itosi

Iji le to be ge tofe dawon sinu omi

Eru ba awon omo eyin re won si nkigbe

Olugbala yo lojiji o rin lori okun

Owa dawon loun

Emi ni mase beru omo


Emi ni mase beru omo

Omo mi ma gbo o

Emi ni mase beru omo

Omo mi ma gbo mi

Emi ni mase beru omo

Emi ni mase beru omo


O ko kawon mimo ma ma beru

Ki won si so ireti nu

Bawo oko tin rowo re

Olugbala ayi lopin


Peteru lo fe se bi jesu oluwa wa

O loun fe rin lori okun

O loun fe gun iji leshin

Olorun ni ko wa

Bo shey gbese meji lori okun iberu ba de

Ni peteru ba bere si ni rin sin omi

Yesi eyin tele mi ni gbagbo pe

Eyin pemi bi oluko ni

Be eyin ti ri ise iyanu lorisirisi

Peteru kilo wa de to fin beru niwaj olorun


Emi ni mase beru omo

Ninu riru omi ati iberu aye

Oni gbagbo ma gbo mi

Aro pe lomi odi okusu

Ijogbon po latan odi egbo ntarigi

Ko dele nfi ese wo igboro

Mo ma shiye mi o

Oya ka jo shoro olorun

Gbangba leyi odo gbangba lan ta gadangba si

Aye le ma binu

Won le ma binu ipin

Won le ma binu ogo

Olorun sope oun ni

Oun gbe pharaoh laya le

Kogo olorun ba le han faye ri

Emi ni mase beru omo


Bi gbogbo aye dite mo wa

Won gbodo teriba fun oluwa

Eyin omo ijo mimo

E did eke yin oluwa

Hallelujah ni orin wa

Hallelujah wa ninu ise wa

Bi aye fe

Bi aye ko

Won a teriba fun oluwa

Emi ni mase beru omo


Agan ma ron mo

Mase beru aye yi

Oni segun ni o e romo bi

Amo onisegun nla ni jesu

Omo mase beru rara o sha ti gbagbo ninu olorun

Bo tie tipe o lako aja

Toni iwo agbebo adiye

Mase beru mase foya o

Emi ni mase beru omo


Nitori ** ono nigba ishoro

Lati se ise re

Ono re enikan mo

Awa ma ridi ni

Alayi gbagbo won yio shino

Won kose oluwa

Sugbon awa to gbo oluwa pon

Aki yio pofo laye

Emi ni mase beru omo


Ami wo leyin tun wa

Oro yi lo bi dafidi lere

Nigba ogun sal le koko

Ogn ota aleni ma deyin

Dafidi ti bere sini beru oti fe ma ro ra re pin

Oba ti sora re deru aye

Olori ogun ti bere sini shojo

Koda baba olorin o le korin mo

Iberu ati ifoya ti gbakoso

Amo lojo kan lajaga nbo

Iberu ojo ba fo lo

O ranti agbara to fa imotekun ya

O ranti okuta marun to feyin omiran konle gbonrangondon

E ono iyanu ni baba gba o

Ti dafidi fi fori so ** ota lara


Oba gbeni doke ayo mo ma ro mo o

Oba gbeni doke ayo mo ma ro mo o

Ibi osin mi de me mo pe mo le de laye

Iwo la gbemi bori

Won binu ipin

Won bin ogo

Ogo iwo olorun gbami o baba


Oba gbeni doke ayo mo ma ro mo o

Oba gbeni doke ayo mo ma ro mo o

Ibi osin mi de me mo pe mo le de laye

Iwo la gbemi bori


Ota gbe koto ibanuje le

Iwo olorun lo dipa lofo

Ah oba gbeni doke ayo mo ma ro mo o

Oba gbeni doke ayo mo ma ro mo o

Ibi osin mi de me mo pe mo le de laye

Iwo la gbemi bori


Ma foya ni apa jesu

Kosi oun iberu mo

Ino tin jo ko le sun mo o

Imo esu ti di wiwo mo le

Mo ro mo agbelebu re

To gba on gbogbo sa asan

Ma beru iwo okan mi

Ayanfe ninu eje jesu

Emi koni fi o sile

Jesu olugbala mi

Ninu re ni iye mi wa

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status