Majemu Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1998
Lyrics
[ti:02 Majemu]
Majemu to ti bami da ma gbagbe
Ileri to se fun mi ma gbagbe
Majemu to ti bami da ma gbagbe
Ileri to se fun mi ma gbagbe
Mon wo oju re baba tete dami loun
Mon ke pe olorun wa se temi
Omo okunrin w’owo baba re
Omo obinrin w’owo iya re
Mon woju re baba mimo se temi
Bi agbonri tin ni ele sibado omi
Be lokan mi mi ele si o
Titi o fi se temi mi o ni sinmi o
Omo kiniun ama se alaye ni
Ebi asi ma pa won o baba
Sugbon awa ta gboju le o a oni shala ini oun to dara
Oni ma ma bo ifa mo
Me ma ma bo ifa mo o
Oni ma ma se ogun
Me ma ma bawon se ogun mo o
Oni ma ma se ebo mo
Me ma ma bawon se ebo mo o
Oni ma ma bawon jawe mo
Me mo ma bawon jawe mo
Dami loun
Dami loun
Dami loun o baa mi
Mu ileri ayo se
Mu ileri ayo yi se
Mu ileri ayo se
Karaye ma bere p’olorun mi da o
Mu ileri ayo se kan kan
Kan kan o
Olorun mi o
Mu ileri ayo se kan kan
Kan kan o
Aye npe mi lomo olorun
Baye oba ri ise ati ise iyanu
Won oni gbagbo
Je ki aye rogo re lara mio
Jeki ota mope mo ni l’olorun
Je ki aye mope mo ni o ni baba o
Je k iota mope mo ni l’olorun
Ileri re nio se
Majemu re toba mi da
Ma gbagbe o
Ma gbagbe o
Ma gbagbe o
Ma gbagbe o
Olorun iyanu