Ranti Mi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2009
Lyrics
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi ninu anu re
Fiseun ife re gba mi
Ongbe re gbe okan mi
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi
Ranti mi oluwa o
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi ninu anu re
Fiseun ife re gba mi
Ongbe re gbe okan mi
Oluwa ma gbagbe mi o
Gbo okan mi olorun
Fiye si adura mi
Nigbati opin aye wa
Ti emi omije pe o
Nigbati ore aya mi
Fami losi apata ti *** aye mi wa
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi
Ranti mi oluwa o
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi ninu anu re
Fiseun ife re gba mi
Ongbe re gbe okan mi
Oluwa ma gbagbe mi o
Nitori iwo ni oti se abo fun mi
Ati ile isho agbara lowo ota mi
Emi o joko ninu ago re lailai
Jeki emi mi abo ni iye apa re
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi ninu anu re
Fiseun ife re gba mi
Ongbe re gbe okan mi
Oluwa ma gbagbe mi o
Nitori iwo olorun oti gbo ebe mi
Iwo ti fi ogun awon ti o beru
Oruko re fun mi
Iwo o gba emi oba gun
Ati ojo ni ati iran di iran ni
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi ninu anu re
Fiseun ife re gba mi
Ongbe re gbe okan mi
Oluwa ma gbagbe mi o
Wun o ma gbe iwaju olorun lailai
Pese anu ati otito
Ni o ma se itoju re
Emi yio ma korin iyin si oruko re lailai
Ki emi ki o le ma san eje mi ni ojojumo
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi ninu anu re
Fiseun ife re gba mi
Ongbe re gbe okan mi
Oluwa ma gbagbe mi o
Ranti mi oluwa
Ranti mi oluwa
Oluwa ma gbagbe mi