Apata Ayeraye Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2010
Lyrics
[ti:03 Apata Ayeraye]
Oluwa ire ni apata ayeraye o
Oluwa ire ni apata ayeraye o
Sheyi bi isadi mi nigba to ye mi
Jeki omi ati eje to nshon ni iha re
Kole se etutu si ese mi (x2)
Wemimo o wemi ni awe mo o
Wemimo o wemi ni awe mo o
Mo jewo ire koja mi gbogbo
Moti di atunbi ninu re
Mo jewo ire koja mi gbogbo
Moti di atunbi ninu re
Baba gbo igbe mi o
Baba nu omije mi nu o o o o
Oluwa yio wa shami ti lailai mi
Yio wa si tun oju rere mo bi
Anu re alo ileri re a ye lailai bi
Olorun jare o
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Oti gbagbe w ape to ni Nigeria yi o baba re
Yara gbawa olorun iyanu
Oshika lo gba ijoba lowo asheni abani daro
Yara gbawa olorun iyanu
Ebi npa olododo alayise ododo won yokun
Yara gbawa olorun iyanu
Adiye wa ba lokun ara o rokun ara o ro adiye
Yara gbawa olorun iyanu
Ba tie lolugbeja eni e lolorun o jare baba
Yara gbawa olorun iyanu
Shebi ere lo gb’omo Israel l’oko eru o
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu
Yara gbawa olorun iyanu