Last Advice (Ikilo Ikehin) Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2007
Lyrics
[ti:03 Last Advice ( Ikilo Ikehin)]
Lati kekere loye kati peka iroko o
Tori toba dagba tan ebo ni o ma gba o
Lati kekere loye kati peka iroko o
Tori toba dagba tan ebo ni o ma gba o
Igbanla dogi
Abiamo toju omo
Omo ta o ko ni doju tini
Won ti kekere ya ashewo
Won ti wo egbe seyun seyun
Igbanla dogi
Abeni loramo
Aminotu tentenji
Efe baye are yin je
Igbanla dogi
Tara ba baje tan talara nio da o e
Igbanla dogi
Ori okere koko lawo o
Ba awi fuun omo eni agbo
Ati kekere ni igbagbo tin k’omo re lesin o
Eni bimo ko to o
Tori eni ko tori ola ni
Lati kekere loye kati peka iroko o
Tori toba dagba tan ebo ni o ma gba o
Lati kekere loye kati peka iroko o
Tori toba dagba tan ebo ni o ma gba o
Igbanla dogi
Abiamo toju omo
Omo ta o ko ni doju tini
Won ti kekere ya ashewo
Won ti wo egbe seyun seyun
Igbanla dogi
Abeni loramo
Aminotu tentenji
Efe baye are yin je
Igbanla dogi
Tara ba baje tan talara nio da o e
Igbanla dogi
Bode ba rose riiya botaperan kooni fun enikan je o
Bi abiyamo ba rose roya bami no omo mi o den olomo
Omo tabi ta o to
Omo tabi ta o to
Boya la le rere omo je
B’omo ban be ni majesin lo se to lose to
Bo ba dagbalagba layi ko
Oma dabi eja gbigbe ta o le ka ni
Omo mi gbo temi
Iwo ni ire aye mi o
Omo ni gbo temi
Iwo ni ere aye mi o
Ti mo ba dogbo alayi lagbara
Shebi wa le toj ara re
Bi mo ba dagbalagba bimo ba lo
Omo mi wa le d’aye re se o
Lati kekere loye kati peka iroko o
Tori toba dagba tan ebo ni o ma gba o
Lati kekere loye kati peka iroko o
Tori toba dagba tan ebo ni o ma gba o
Igbanla dogi
Abiamo toju omo
Omo ta o ko ni doju tini
Won ti kekere ya ashewo
Won ti wo egbe seyun seyun
Igbanla dogi
Abeni loramo
Aminotu tentenji
Efe baye are yin je
Igbanla dogi
Tara ba baje tan talara nio da o e
Igbanla dogi