Mo Gb’ọ́lá Wá Lyrics
- Genre:Spirituals
- Year of Release:2022
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Mo Gb’ọ́lá Wá - Sola Allyson
...
I'ba olola toju
Olola enito dami
Timo se wo
Gbogbo ise lobu
Ola fun o mo join won
Mogbola waa.
Iba olola toju
Olola enito dami
Timo se wo
Gbogbo ise lobu
Ola fun o mo join won
M'ogbola waa.
M'oghola wa
M'ogbola wa
M'ogbola wa
fun iyere ye
boti be, yo ma be
ole ye pada, iyera ye
iyera ye, iyera ye
iyera ye, mo gboola wa
boti be yo ma be, ole yi pada iyera ye
iba re, oba to laye
iba fun ooo oba to olorun
ori ite loju kole
to ti pase eee iyera ye
ni pase re ni ilekun ojo si
eni gun sun mo lawo
mose ba re
imole un tann
lati agbala wa
agbala wa ta ti Pele ire
awon ise ari,
won yobo re
ni agbala
iyera ye