Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2019

Lyrics

Mimo ni o


Written by Sola Allyson

Produced by Mr Wols


Mimo ni O mimo ni O o mimo

Mimo ni O mimo ni O o mimo


Ad lib: Oluwa Olorun Eledumare t'O po n'ipa ati agbara

Gbogbo iseda nso bee emi naa mo so bee

Lat'ogbun emi i mi


Mo juba Re Oba mimo

Mo wole fun Oba toto

L'eyin Re, ko si o

Iwo nikan ni Oba

(Repeat)


Ad lib: Awamaridi Oluwa

Iwo t'O wa n'ipekun imole, Iwo ni ekun ola, ekun ogbon, ekun agabara

Oba t'Ó joko s'ori Ite, Oba t'Ó wa l'ori obiri aye maa s'ola a Re lo

Aye ati orun nbo O, kos'elomiin t'o ye ko gba ijuba wa bi o se'Wo


Mo wari fun O o Olola

Imole t'O ntan s'inu ookun mi ogo f'ooko Re

L'eyin Re ko si o

Iwo nikan ni Oba

L'eyin Re ko si o

Iwo nikan ni Oba


Ad lib: Pelu iwariri lat'ogbun emi mi

Kos'elomiin Iwo ni, l'eyin Re Iwo naa ni

Olugbemiro, Olusaaanuumi, Olukemi, Olufunmilebun, Olugbemiro, Iwo nikan Olutimileyin


Mimo ni O mimo ni O oo mimo

Aye ati orun ns'oro ogo Re a n f'ise owo Re han, Iwo, mimo

Mo da ohun mi po mo gbogbo ise Re, emi, emi i mi ati eemi i mi a nyin O nigbagbogbo, Oba t'Ó wa n'ipekun ola, ipekun ogo, ipekun agbara, ipekun ewa Iwo nikan ni Oluwa

Pipe naa l'O je Oluwa


Pipe ni O, pipe ni O o pipe

(Ta l'o le yo kuro ninu Re nigbat'a o tie mo)


Yiye ni O yiye ni O o yiye

(Iwo naa l'O wa fun'ra Re Iwo ni Oluwa, Odo Aguntan t'O joko s'ori Ite o yiye)


Tito ni O tito ni O o tito

(Tito ni O Eleda gbogbo iseda, Olutoju gbogbo eniyan, Olorun gbogbo eran ara, Eniti ngbo adura odo Re l'a nwa Iwo ni)


Gigun ni O gigun ni O o gigun

(Oba t'O joko s'ori obiri aye, O fi aye so'le s'ori awon isan omi, aye ò le ri lailai ko le ri ise e Re ni, gigun, o gun lailai)


Mo juba Re, Oba mimo, etc


Ad lib : Emi mi n juba Re nigbagbogbo

L'eyin Re kos'elomiin

I confess kos'elomiin

Olorun Eledumare t'O po n'ipa ati agbara Iwo ni o

Olorun awon'mo ogun Iwo nikan

Tani m ba juba bi o se'Wo

Olori egbegberun ogun awon angeli Iwo ni

Oluda aye kos'elomiin

Aseda gbogbo eniyan, Olorun gbogbo ede, Olorun gbogbo eya

Emi mi, eemi mi, ati emi naa

Imole t'o ntan ti ò le ku lailai

Olugbemiro, Olusaanuumi, Olugbamila, Oluyomi ninu okunkun

L'eyin Re ooo

Tani m ba sin bi o s'Enit'O gba mi la, Eniti mi ò ri sugbon ti mo r'ise Re ninu aye mi


Iwo nikan ni Oba


Ad lib: Olorun gbogbo araye Iwo nikan ni

Olutoju gbogbo eniyan Iwo nikan ni

Mo ki O ki O Iwo nikan ni Oba

Maa s'ola Re lo, maa s'ola Re lo kos'elomiin You Are The only One, You Are The only One Iwo nikan, Holy, mimo mimo ni O Iwo ni Oba


Iwo nikan ni Oba.




--- www.LRCgenerator.com ---

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status