Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2015

Lyrics

Nipa ipa ko kii s'agbara l'oro se ri b'o se ri

B'o ti wu ko ri oluwa s'olododo f'awon to gba a gbo

Oye aye o ye ni to sugbon o da wa loju

Alaanu l'olorun wa

A gbe ni leke oluke ni oluyan ni sola

Aseyiowu o se o Baba t'o fi wa dara iyanu

Iba iba iba

Iba o

Iba f'olorun eledumare to l'ogo oooo iba

Iba Iba Iba naa ni o Iba o

Iba Iba Iba o

A juba a juba f'olorun to ni gbogbo ogo oun ni Iba o

Iba l'awa f'aye wa ju oo Iba o

Iba a juba Re Iwo nikan lo ni gbogbo ijuba a wa Iba o

Iba Iba Iba

Ope ni fun o edumare oba to laye

Adani magbagbe oba oke to segun fun wa

Bi ko ba se wo too seyi fun wa ki la a ba wi o

Ope wa ree o oba to to gb'oju le

A mo riri oore t'Oo se fun wa o

Oba to to gb'oju le

Okeere ni mo gbe wa o

Mo gburo ise Oluwa

Ta lo dabi Re ninu aanu adani ma gbagbe eni

Bi'da keji ba sele oo sa ma j'olohun lo ni

O ka wa m'awon t'oo pe, t'oo yan

Oba to to gb'oju le

O ka wa m'awon t'oo s'aanu fun

A o le dupe tan lai lai lai lai


You are the Lord above all the earth

Kabi o o si o kabi o osi o

You are the Lord above all the earth

Kabi o o si o kabi o osi o

Oju mi ti ri eti mi ti gbo

Iyanu re yi aye ka

Mo gbo ninu eri awon eniyan mimo

Mo ri ninu itan emi gangan ni itan

Gbogbo ise re daa da'a da'a da'a ni

Aburu kankan o t'odo Re wa

Ohun gbogbo lo le yi pada

Sugbon rara t'ododo ee ko


Kabiyesi oooo mo se ba Re

Oba to ju gbogbo oba lo

Kabiyesi ooo

Kabiyesi o mo se 'ba re

Oba to ju gbogbo oba lo

Afuye gege ti o see gbe

Jigbinni jigbinni bi ate ileke

Kabiyesi o mo se 'ba Re

Oba to ju gbogbo oba lo

Afuye gege ma ma see gbe

Jigbinni jigbinni bi ate ileke

Kabiyesi o mo se 'ba Re

Oba to ju gbogbo oba lo

Mo se 'ba re o mo se 'ba Re

Mo f'ori bale mo gb'owo soke

Mo se'ba re o mo se 'ba Re

Ni 'rele okan mi ni mo wari

Kabiyesi o mo se 'ba Re

Oba to ju gbogbo oba lo

Kabiyesi o

Kabiyesi o mo se 'ba Re

Oba to ju gbogbo oba lo


Aigbagbo bila temi l'Oluwa

Oun yoo si dide fun igbala mi

Ki n sa ma gb'adura

Oun o se 'ranwo

'Gba Krist' wa l'odo mi ifoya ko si

B'ona mi ba su oun lo sa n to mi

Ki n sa gboran sa oun o si pese

B'ona mi ba su o oun lo sa n to mi

Ki n sa gboran sa oun o si pese

Bi 'ranlowo eda

Bi 'ranlowo eda gbogbo saki

Oro t'enu re n so yoo bori dandan

Hallelujah

Hosanna

Hallelujah

Hossanah

Hallelujah l'awon orun nke

Hossanah

Awa aye naa nke tiwa hallelujah

Hossanah

Hallelujah

Hossanah hossanah hossanah l'awa nko

Hallelujah Hossanah

Gbogbo iseda n f'ori bale f'ooko re Hallelujah

Hossanah

Hallelujah

Hossanah

Our Father

We bless You

Olutoju wa we bless You

We bless You

Eni to l'emi to fun wa mi we bless You

We bless You

Eni t'o fi 'ranwo fun wa we bless you

We bless you

Eeeh oluwa eeeh ehhh Oluwa

Eeeeh oluwa o b'ona ba su

Oluwa f'ona han wa, Oluwa o

Eeeh Oluwa eeeeh ehhh oluwa o

Eeeeh oluwa o b'ona ba su

Oluwa f'ona han wa oluwa o

Ife t'o fi han ko je ki n ro pe

Yio fi mi sile ninu wahala

Oun to mu mi de bi s'olododo lati sun mi siwaju

Ko ni fi mi sile bo ti le wu ko ri o


Iranwo ti mo si

Iranwo ti mo si n ri lojojumo

O ki mi l'aya pe emi yoo laaja

Olorun agbaye

You are mighty

Olorun to wa ninu awon orun to ju awon orun lo you are mighty

Ori obiri aye lo n gbe imole lo fi saso bora o you are mighty

O f'orun se 'le o f'aye s'apoti itise maa s'ola re lo you are mighty

You are mighty you are wonderful you are awesome oruko re niyen you are mighty

Olorun agbaye you are mighty

Sebi 'wo lo f'oju orun saso bora

Olorun agbaye o you are mighty o

Olorun agbaye o you are mighty

Sebi 'wo lo f'oju orun saso bora

Olorun agbaye o you are mighty o

Oruko oluwa ile iso agbara ni

Olododo sa wo'nu re o ri iye

Emi naa mo sa wo'nu re mo ri iye

Oruko Re ti niyin to oluwa oluwa

Oluwa oluwa wa oruko re ti niyin to

Oluwa oluwa oluwa

Oluwa oluwa wa oruko re ti niyin to


Alagbara l'olorun wa

Agbara agbara agbara yi po o agbara

Oba to ba riru omi okun wi agbara Re po

Agbara agbara agbara yi po o agbara

A wo 'gba aarun ma gb'eje l'ooko Re

Agbara agbara agbara yi po agbara

Oba to f'aanu tan 'mole s'ona awon to gb'oju s'oke si

Agbara agbara agbara yi po a agbara

O f'agbara gba ni lowo alagbara gbangba ti n f'owo agbara je ni niya

Agbara agbara agbara yi po o agbara

Gbogbo iseda n wariri ni'waju agbara Re

Agbara agbara agbara yi po o agbara


Iba o

Iba f'Olorun Eledumare to ni gbogbo ogo (Iba)

Iba Iba a (Iba)

A juba a juba, gbogbo ijuba wa tire ni (Iba)

Olorun to ni gbogbo ogo iba f'ooko Re (Iba)

Gbogbo iseda n f'ori bale ni'waju Re (Iba)

Iba Iba Iba a

Ise Re po o po o po o po gaan ni (Iba)

Awon ise iyanu t'oo ti se, ta lo le ka won tan? (Iba)

Ta lo le so ewa Re to po to po gaan ni? (Iba)

Iba Iba Iba Iba (Iba)

Gbogbo eemi mi gbogbo wiwa mi tire lo je mo juba (Iba)

Titi aye ni ma ma se'ba Re lojojumo (Iba)

Maa sin o d'opin igba mi Iba Iba (Iba)

Iba aaa

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status