Mímọ́ Medley (Live) Lyrics
- Genre:Spirituals
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Mímọ́ Medley (Im'oore) (Live) - Sola Allyson Obaniyi
...
Mimo mimo mimo
si olodumare oju elese kole ri ogo re
Mimo mimo mimo
si olodumare oju elese kole ri ogo re
mimo mimo mimo
si olodumare oju elese kole ri ogo re
ma joba lo oluwa
ma joba lo (kabiyesi olola maje oba lo)
ma joba lo oluwa (kosi elomiran leyin re baba imole ma joba lo)
oba ta kole ro loye
oba tako le ro loye
alagbara tako le segun ni
ijoba re dun mowa ye ye o
ma joba lo oluwa
ma joba lo oluwa (bi o ti ye wa ni atin yin o oluwa ma joba lo)
wa gba ope ati ogbe okan wa
ma joba lo
ao ri ori sugbon ari ninu ise re (ma joba lo)
oba ta kole ro loye
oba tako le ro loye
alagbara tako le segun ni
ijoba re dun mowa ye ye o (eni to ni emi mi ma... )
ma joba lo oluwa
ola lewo laso
ogo laso ileke
iyin legun lesin
awamaridi o olodumare (ola....)
ola lewo laso (ola lowo)
ogo laso ileke
iyin legun lesin (iyin legun lesin)
awamaridi o olodumare
ola lewo laso
ogo laso ileke (you ride on the wings of our praise, olorun awon omo ogun, unquestionable olodumare )
ola....
ola lewo laso
ogo laso ileke
iyin legun lesin
awamaridi o olodumare
talaba fi o we
talole ba o dogba
talaba fi o we
talole ba o dogba (olorun toju olorun lo)
olorun to ju olorun lo talaba fi o we (olorun to ju olorun lo o)
olorun to ju olorun lo talaba fi o we (talaba fi o we)
talaba fi o we (incomparable, incredible)
talole ba o dogba (unexplainable oluwa olorun awon omo..)
talaba fi o we (indescribable plies)
talole ba o dogba (olorun to ju olorun lo)
olorun to ju olorun lo talaba fi o we (olorun to ju olorun lo o)
olorun to ju olorun lo talaba fi o we
olorun
.
kabiyesi re oluwa
oba to fi imole se aso ibora