Wá Wọlé & Worshiṕ (Live) Lyrics
- Genre:Spirituals
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Wá Wọlé & Worship (Live) - Sola Allyson Obaniyi
...
Eyin Oba ogo, On ni Olorun
Yin fun 'se 'yanu ti o ti fihan
O wa pelu awon ero mimo l'ona
O si je imole won l'osan l'oru.
E yin Angel 'didan, lu duru wura
Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re
Ni gbogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo
Ise re y'o ma yin
Ise re y'o ma yin
Fi ibukun fun Oluwa okan mi
Eyin Ni oluwa, Jehovah
Eyin Ni oluwa Oba wa
Eyin Ni Oluwa, Jehovah
Eyin Ni Oluwa oba wa
Eyin Ni Oluwa o, Jehovah
Eyin Ni Oluwa O, Oba wa
Eyin Ni Oluwa, Jehovah
Eyin Ni Oluwa, oba wa