Sola Allyson's Classics (Live) Lyrics
- Genre:Spirituals
- Year of Release:2020
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Sola Allyson's Classics (Live) - Sola Allyson Obaniyi
...
Olohun kii mai se ibi
Olohun kii mai se ibi
Olohun kii mai se ibi
Olohun kii mai se ibi
Gbogbo ohun t’olohun da
Dara Dara ni
Botilewu ko joo ibi to
Ire lo ma ja si
A ni lati bebe fun oye orun o
Ka le rin arin ye laye
A ni lati bebe fun oye orun o
Ka le rin arin ye laye
Aseyi owu lolorun
Sugbon sibe sibe ire ni
All things are working together for your good
Sibe sibe ire ni
Bo ban gba ire lojojumo
Ma yo layo ju
Bo ban gba ibi akunwosile
Ma fi were pe eleda lejo
Eyi to wu koje tire
All things are working together for good
Olohun kii se ibi