Loading...

Download
  • Genre:Spirituals
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Mímọ́ Ni Ọ́ (Live) - Sola Allyson Obaniyi

...

mimo ni o

mimo ni o, mimo ni o, mimo (x2

Oluwa Olorun Eledumare, topo nipa at'agbara

Chris: mimo ni o....

Gbogbo iseda son be, emi naa so be

Lati ogbun emi mi, mo juba

Mo juba re, oba mimo

Mo wole fun o, oba toto

Leyin re e, kosi o

Iwo nikan ni oba (x2

Mo wari fun o olola, imole Titan sinu okun mi, ogo foko re

Leyin re e, kosi o, iwo nikan ni oba (x2

Mimo ni o, mimo ni o, mimo

Aye ati orun nsoro ogo re, an fi ise owo re han

Iwo mimo

Mo da ohun mi pomo gbogbo ise re, emi, emi mi ati emi mi, ansi o nigbagbo

Oba towa ni ipekun ola, ipekun ogo, ipekun agbara, ipekun ewa, iwo ni agbara

Pipe loje naa Oluwa

Pipe ni o, pipe ni o, pipe e (x2

Yiye ni o, yiye ni o, yiye

Tito ni o, tito ni o, tito

Gigun ni o, gigun ni o, gigun

Mo juba re, Oba mimo

Mo wole fun oba toto

Leyin re kosi o, iwo nikan ni Oba

Mo wari fun o, olala, imole to tan sinu okun mi, ogo foko re, leyin re e, kosi o

Iwo nikan ni Oba

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status