Akosile Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Akosile ti duro akosile o le tase
Oun toluwa ba se eda kan o le yi pada
Ibi ori gbeni lo kese ma sini lona
Ohun to wun eleduwa lo da fun wa
Ati bi ati re to sele lala eda kan o le ye
Akosile ti duro akosile o le tase
Ayanmo eda ti duro kirakita o dola laiye
Gbogbo eto olorun ko seni to le ba tu to
Gbogbo wa la sare kiri pe ka lola ka je eniyan
Sugbon ta lo le mo ibi ori da ni si
Ati bi ati ire to sele lala eda o le ye
Akosile ti duro akosile o le tase
Wa ba mi se
Wa bami se baba ko ma se le mo mi
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da
Kadara eda ti duro ife eda o le ye lai
Ona to ba wu olorun oun lo le muse ka to
Ori e o dade o fe do ba o wa ba ayanmo jija ka di
Bo ti wun eni toda le lo se se foo yin si
Ati bi ati re ton sele lala eda o le ye
Akosile ti duro akosile o le tase
Eniyan ma yo ra e lenu
Ko y agba fun olorun lo so
Wo omo meji ta bi lojokan
Ayanmo ototo lo yan
Onise ika se orire onise ire wa tosi
Awa be olorun lere je
Bo ti wun olorun lo se oror
Ko seni to le da lejo
Akosile ti duro akosile o le tase
Wa bami se o baba ko ma se le mo mi
Kaiye mi ma koro bi ewuro ara ire ni ko fimi da
Oro olorun ede ni ileri re o le ye lai
Oun toluwa ba pinu ife ota kan o le pada
O ti pinu pe kin sori re pe kin lola kin je eniyan
Oun toluwa ba ko ko seni to le yi
Bo ti wunoluwa lo se’oro oun lo layo ati ola
Akosile ti duro akosile o le tase
Wa ba mi se
Wa bami se baba ko ma se le mo mi
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da
Wa ba mi se
Wa bami se baba ko ma se le mo mi
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da
Wa ba mi se
Wa bami se baba ko ma se le mo mi
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da
Ma fi mi dara
Ara ire ni ko fi mi da
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da
Kaiye mi ma koro bi ewuro
Ara ire ni ko fi mi da