Akosile Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:1998
Lyrics
Akosile - Sola Allyson Obaniyi
...
akosile ti duro
akosile ole tase
ohun toluwa base, eda kan ole Yi pada
ibi Ori gbenilo, kese ma sini Lona
ohun to wun eleduwa lol Le Yan fun waaa
ati ibi ati ire ton sele laala eda ole ye e, akosile ti duro koletase ooo
ayanmo ede ti duro,kirakita o Dola laye gbogbo eto olorun ko seni to le ba tunto
gbogbowa lansare Kiri pe kalola ka jeniyan
sugbon talo le mo ibi Ori dahun sim
ati ibi ati ire ton sele,lala eda ole ye e akosile ti duro ko le tase oo
wa bamise
wabamise oo baba
koma see le mo mi
ka ye mi ma Koro bi ewuro
Ara ire ni ko fimi da
kadara eda to duro
ife eleda ole ye Lai
ona to ba wun olorun
ohun lol Le mu ese eda too
Ori e o Dade ofe joba owan ba ayomo jijakadi
bo ti wun Eni todale lon se n foyin si
ati ibi ati ire ton sele
lala eda o le yeee akosile ti duro ko le tase oo
eniyan ma yo Ra e lenu
koya gba fun olorun loto, wo Omo meji ta bi lojo kan ayanmo ototo loyan,oni Ika sorire onise ire wa tosi
awan bi olorun lere bose je
boti wun oluwa lonsoro,kosi Eni to le daa lejo akosile ti duro kole tase oo