Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2012

Lyrics

Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo

Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo


Igba oro ki fo

Awo oro ki ya

Oun taba se

La o royin

Omo adamo se rere


Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo

Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo


Igba oro ki fo

Awo oro ki ya

Oun taba se

La o royin

Omo adamo se rere


Ile aye ile asan

Afowo ba file sile ni

Showo loni teni kan oni ri

Baba landlord e ro ra

Mafi ile aye ni tenant lara

Toba ku won a lole leyin re

Aunty tenant o

Se inu yin di ni fa

Wo bo se so ile oni le da

Ise owo ko ranrun rara

O ba dakun ko yi wa re

Pada

Ko ma ba kabamo

E e


Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo

Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo


Igba oro ki fo

Awo oro ki ya

Oun taba se

La o royin

Omo adamo se rere


Gbogbo agbani si ise

Ton fi ise ni awase lara

Obinrin nikan lo fe fun ni ise

Koba le wo tibe labe aso

O ma le gbe jombo

Oga alagbere ko lo jawo

Eni jogun iya o

Omo re a je nibe

Tori igba oro ki fo

Awo oro ki ya

Iyan ogun odun

Shin joni lowo


Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo

Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo


Igba oro ki fo

Awo oro ki ya

Oun taba se

La o royin

Omo adamo se rere


Ewo baale ile

To fi omo aya sile

Ko toju won

O dara nita

Ko dara nile

Oti di father christmas sita

Omoge ati oti lo fin shaye

Ayinitelorun lo wo bi aso

Esan a ke o

Esan a ke jare

Oun to ba se

La o royin

Omo adamo se aye re


Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo

Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo


Igba oro ki fo

Awo oro ki ya

Oun taba se

La o royin

Omo adamo se rere


Ojo melo la fe lo laye

Ara mi ta fin wo ewu iri

Boti wu ko wale aye moya to

Akuko a ko leyin re

Lojo kan

Bo ti wu ko lowo laye

Akuko a ko leyin re

Lojo kan

Bo ti le wu ko lagbara to o

Akuko a ko leyin re

Lojo kan


Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo

Eniyan se rere

Tori ojo ati sun re

Eniyan se rere

Ko ma ba kabamo


Igba oro ki fo

Awo oro ki ya

Oun taba se

La o royin

Omo adamo se rere

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status