Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2012

Lyrics

Olori ijo torun

Layo la wole fun

Kiwo to de

Ijo taye

Yio ma korin iyin torun

Agbe

Okan

Wa soke

Pelu ro toni ibukun

Awa ki gbe

Awa fi iyin

Fun olorun igbala wa


Olori ijo torun

Layo la wole fun o

Olori ijo torun

Layo la wole fun o

E baba ki iwo to de

Awa ijo taye

A o ma korin orun

Olori o


Olori ijo torun

Layo la wole fun

Kiwo to de

Ijo taye

Yio ma korin iyin torun

Agbe

Okan

Wa soke

Pelu ro toni ibukun

Awa ki gbe

Awa fi iyin

Fun olorun igbala wa


Kabi o osi

Eledumare oba toto

Ogbe ninu ogo

Eleruniyi

Oba lori oun gbogbo

Kabi o osi

Eledumare oba toto

Ogbe ninu ogo

Eleruniyi

Oba lori oun gbogbo


Kabi o osi

Eledumare oba nla

Kabi o osi

Eledumare oba nla

Sebi iwo lo lano

Lo loni

Lode lojo gbogbo

Obirikiti aji pojo iku da

Adake dajo

Ani bo se wun o

Lode un se akoso o

Gbogbo aye

E pe kabiyesi o


Kabi o osi

Eledumre oba toto

Ogbe ninu ogo

Eleruniyi

Oba lori oun gbogbo

Kabi o osi

Eledumre oba toto

Ogbe ninu ogo

Eleruniyi

Oba lori oun gbogbo


Oba to damisi

Eleruniyi

Oba pipe

Iranlowo alayini

Alade wura

Iwo ni mo f’ope fun o

Alagbada ino

Alawotele orun

Oba ton se mimo

Ani bo se wun o

Lo de nse ola re

Lori oun gbogbo

Epe kabiyesi o


Kabi o osi

Eledumre oba toto

Ogbe ninu ogo

Eleruniyi

Oba lori oun gbogbo

Kabi o osi

Eledumre oba toto

Ogbe ninu ogo

Eleruniyi

Oba lori oun gbogbo


Ara ewa o

Kajo yin jesu logo

Olore o

Iwo l’ope ye o

Ara ewa o

Kajo yin jesu logo

Olore o

Iwo l’ope ye o

Ore re po

Oju yorin okun lo

Inu aye mi o

Mo mu ope mi wa

Ore re po

Oju yorin okun lo

Inu aye mi o

Mo mu ope mi wa


Oba mimo ti fun layo

Emi ti dagbada ope

Gbogbo eniyan toba re

E tele mi kalo dupe o


Oba mimo ti fun layo

Emi ti dagbada ope

Gbogbo eniyan toba re

E tele mi kalo dupe o


Oba mimo ti fun layo

Emi ti dagbada ope

Gbogbo eniyan toba re

E tele mi kalo dupe o

Ijo ope ya


Oba mimo ti fun layo

Emi ti dagbada ope

Gbogbo eniyan toba re

E tele mi kalo dupe o


Kilo mu wa o

Ope ni mo mu wa

Siwaju re oba iyanu

Nigbati mo weyin wo

Mo rowo re o

Oba nla


Ope ni mo mu wa

Siwaju re oba iyanu

Nigbati mo weyin wo

Mo rowo re o

Oba nla


Igba mo wo ipinle ese

Aye mi baba

Ti mo wo ibi to tin bami bo

Igba ti won pada leyin mi

Adanimagbagbe duro ti mi

Gbonyin gbonyin

A iranlowo alayini o

Mo rowo re o

Oba nla

Iranlowo alayini o

Mo rowo re o

Oba nla


Kilo muwa o


Ope ni mo mu wa

Ope

Ope

Ope

Siwaju re oba iyanu

Siwaju re oba iyanu o

Nigbati mo weyin wo

Mo rowo re o

Oba nla


Mo mu orin ope

Mo mu ijo ope wa


Ope ni mo mu wa

Siwaju re oba iyanu

Eyin oba afuni ma sinregun

Nigbati mo weyin wo

Mo rowo re o

Oba nla


Olorun ni o baba

Agbani ma gba eje o

Alanu ni o baba

Afuni ma sinregun

Laarin opo eniyan

Loti tami yo

Laarin opo eniyan

Lose mi lore

Laarin opo eniyan

Loti tami yo

Laarin opo eniyan

Lose mi lore


Mo mu ope wa o

Ope ni mo mu wa

Mo mu orin ope wa

Siwaju re oba iyanu

Nigbati mo weyin wo

Mo rowo re o

Oba nla

Ope

Ope

Ope

Ope ni mo mu wa

E bami kigbe ope o

Siwaju re oba iyanu

Mo gbe ope si iwaju re baba

Nigbati mo weyin wo

Mo rowo re o

Oba nla


Jesu iwo loba mi se o

Jesu iwo loba mi se o


Jesu iwo loba mi se o

Jesu iwo loba mi se o

Igba taye rope oti tan fun mi o

Tawon ebi atore tun komi sile

Jesu iwo

Lo se o

Jesu iwo loba mi se o


Aterere kari aye

Eleburuike o

Oba adani waye

Oba tin gborun shogo

Oba tin gbe inu mundia shola

Alagbara giga

Giga

Ni isalu orun

Oba mi asoro matase

Oba mi asoro maye

Olugbeja omo orukan

Iranlowo alayini

Baba awon alayini baba

Oko awon opo

Ose oluwa

Oba tin je mimo

Oba tin wo mimo

Oba tin lo mimo

Ton fi mimo bora bi aso

Jesu iwo loba mi se o

O jare

Jesu iwo loba mi se o

Igba taye rope oti tan fun mi o

Tawon ebi atore tun komi sile

Jesu iwo

Lo se o

Jesu iwo loba mi se o


Ose jehovah

Ose jehovah

O seun baba

Ose jehovah

Ose jehovah

O seun baba

Oba to ranmi lowo

Ose jehovah

O seun baba

E e ose jehovah

O seun baba

You are the rose of sharon

You are worthy oh lord

O seun baba


Ose jehovah

Ose jehovah

O seun baba

E e ose jehovah

Ose jehovah

O seun baba

Aa ose jehovah

Ose jehovah

O seun baba

E e ose jehovah

E kigbe jehovah

O seun baba

Ee ose jehovah

Ose jehovah

O seun baba

Oo jehovah

Eee jehovah

O seun baba

Ose jehovah

Ose jehovah

O seun baba


Okan mi yin oluwa

Iwo ni ireti mi

Nigba taye sope oti tan o

Baba mi gbe iranwo dide

Odoju tota o o o

Odoju ti elegan

Odoju tota o o o

Baba ti doju ti elegan

Odoju tota mi o o

Odoju tota o o o

Odoju ti elegan

Odoju tota o o o

Baba ti doju ti elegan


Kan mi yin oluwa logo

Oba iyanu to wa mi ri

Ogba gbogbo iyin aye ka

Mo ma korin iyin atobiju

Oluwa ope ni fun o

Fun ore ofe to fi pe mi

Jowo di mi mu

Titi dopin

Kin le joba pelu re loke


Kilo se

Odoju tota o o o

Odoju ti elegan

Odoju tota o o o

Baba ti doju ti elegan

Odoju tota aye mi

Odoju tota o o o

Odoju ti elegan

Odoju tota o o o

Baba ti doju ti elegan


Talo dabi ire

Ninu aye yi

Koma soba bi re

Laye l’orun

Ninu alagbara aye o

Tani kafi se akawe re

Olorun oke eri

Mo mu ope mi wa

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o


E Olorun oke eri o

Mo mujo ope wa

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun timi owokoya

Tele mi

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Oba to o doju adura timi

Mo gbegba ope wa

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun tawon olugbeyin loye

Npe toluwa mu sanmi

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun praise generation

Oun lo ba mi se

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun 21days

Ni imesi ile

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Oba to ekun derin

To nu omije mi nu

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun oke eri o

Modupe

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun oke eri

Nilu imesi ile

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Os e

Ose o baba

E olorun ayo

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o

Olorun oke eri o

Modupe

Olorun oke eri o

Mo mope mi wa o


Oya e pariwo

E pariwo

Oti ya e pariwo

E pariwo

E pariwo oruko re

Kaye gbo o

Oyigi yigi oba iyanu

Adagba ma te pa

Ogbani gbani la

Soni d’omo

Baami arugbo ojo

E eee

E pariwo


E pariwo oruko re

Kaye gbo o

Oyigi yigi oba iyanu

Arugbo ojo

Gbongbo idile jeese nla

Oba tin gbani lojo aye koni

Gbani gbani

Gbani gbani la

Soni d’omo

Oya e pariwo

E pariwo


Oti ya e pariwo

E pariwo

E pariwo oruko re

Kaye gbo o

Oyigi yigi oba iyanu

Adagba ma te pa

Ogbani gbani la

Soni d’omo

Baami arugbo ojo

E eee

E pariwo


Ekigbe re

Oba ni

Oba ni o

Oba ni

Arugbo ojo

Oba ni

Oba ni o

Oba ni

Asoro matase

Oba ni

Awimayehun

Oba ni

Oba tin foba je

Oba ni

Tin roba loye ni

Oba ni

Oba tin foba je

Oba ni

Tin roba loye ni

Oba ni

Oba awon oba

Oba ni

Gbongbo idile jeese ni

Oba ni

Oooo

Oba ni

Oba ni

Oba ni

Oba ni o

Oba ni

Oba ni

Oba ni

Oba ni

Oba ni

Oba ni

E kigbe re o

Oba ni

Kaye gbo

Oba ni

Alawo dudu

Oba ni

Kaye gbo o

Oba ni

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status