Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2012

Lyrics

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re


Ose ileri ayo

Fun abraham o

Ose ileri fun elizabeth

Ma je wa mi nu o

Ileri ayo toba hannah se

Lati bi omo alagbara

Olorun ileri muse

Olorun ni o

O mama kin se eniyan

Eniyan lo le se eke o

Baba mi mu ileri ayo re se

Laye mi


Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re


Eni t’olorun ba ti ko

Rere mo laye o

Boti wu kesu ko

Gbogun to o

Yio bori isoro

O so ninu oro re

Pe bi ileri no tile fale

Koni pe mo o

Ko duro koni pe de

Nigbati awon eniyan komi sile

Ti won pe mi ni oniranu

Tewo gba mi o

Iwo lo yo obedi odomu

Lowo esin omo araye

Apoti eri aye mi o

Je ko so eso ibukun

Ileri ayo re laye mi

Kole se o baba

Jare o wa mu se

Gbogbo ileri ayo re

Baba


Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re


Bo se ileri owo

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri omo o fun o

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri ile kiko

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri oko fun o

Odi dandan ko mu se

Ayo igbala pipe nko

Odi dandan ko mu se

Ibale okan ni gbogbo ono

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri ise fun o

Odi dandan ko mu se

Idagba soke ninu ara jare

Odi dandan ko mu se


Ileri ayo

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re


Jesu

Jesu

Asoro matase

Jesu

Jesu

Asoro matase


Bo se ileri owo

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri omo o fun o

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri ile kiko

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri oko fun o

Odi dandan ko mu se

Ayo igbala pipe nko

Odi dandan ko mu se

Ibale okan ni gbogbo ono

Odi dandan ko mu se

Bo se ileri ise fun o

Odi dandan ko mu se

Idagba soke ninu ara jare

Odi dandan ko mu se


Ileri ayo

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re


Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re

Ileri ayo to bami da

Baba mi wa mu se

Gbogbo ileri ayo re


Jesu

Jesu

Asoro matase

Jesu

Jesu

Asoro matase

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status