Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:1999

Lyrics

Okiki

Olorun okiki o

Yagbo yaju

Okiki o

(Ebami pokiki Oba awon oba) Okiki

Olorun okiki o

Yagbo yaju

Okiki o

Kabiyesi Olowo gbogboro iba


Eje kayin Baba o Ologo (Eje kayin Baba o eh eh eh)

Eje kayin Baba o Ologo (Eje kayin Baba o eh eh eh)

Olorun alagbara

Oluwa Olore Jehovah ni Oruko Re (Eje kayin Baba o eh eh eh)


Iba f’Eledumare Olowo gbogboro

Iba Baba Apata Ayeraye

Olorun Emini Emini Emini Emini

Emini maseberu

Arugbo ojo

Openi tin peni sola

Olorun iyanu iyanu iyanu iyanu iyanu ni

Eh eje kayin Baba o logo (Eje kayin Baba o eh eh eh)

Eh eje kayin Baba o logo (Eje kayin Baba o eh eh eh)

Olorun alagbara Oluwa Olore Jehovah li Oruko Re (Eje kayin Baba o eh eh eh)


Malanu ma korin mayin Jesu mi logo logo

Oba to gbami lowo aye

Oba to gbami lowo iku

O gbemi leke abinu eni

Kabiyesi o iba Re

Baba ye eje kayin Baba o logo (Eje kayin Baba o eh eh eh)

Eje kayin Baba o logo (Eje kayin Baba o eh eh eh)

Olorun alagbara Oluwa Olore Jehovah li Oruko Re (Eje kayin Baba o eh eh eh)


Emi olese kemi ma yin Baba

Mi ole se kemi mafiyin fun Oba todaye orun

Oluranlowo Oluranlowo ton dabira ton funni ni jije

Baba mi Jesu mi emi mama wipe eseun

Baba mi Omase (Baba mi Omase o)

Moyin O o (Baba mi Omase o)

Ese mi oko bata (Baba mi Omase o)

Orimi oko fila (Baba mi Omase o)

Taya mi oko gele (Baba mi Omase o)


Instrumental

Ibare Jesu ibare 2x

Mo seba Apataye o ibare

(Oba o) Ibare Jesu ibare 2x

Mo seba Apataye o ibare


Oba Ayeraye (Oba Ayeraye)

Ibere ati opin (Ibere ati opin)

Adeda Aseda (Adeda Aseda)

Olowo gbogboro (Olowo gbogboro)

Eleti lu jara (Eleti lu jara)

Anibi ajere (Anibi ajere)

Eni mimo julo (Eni mimo julo)

Arugbo ojo (Arugbo ojo)

Adagba ma paro oye (Adagba ma paro oye)

Jah Jehovah ni (Jah Jehovah ni)


Iyanu ni iyanu ni (Iyanu ni)

Alagbara giga iyanu ni

Iyanu ni iyanu ni (Iyanu ni)

Alagbara giga iyanu ni

Iyanu ni iyanu ni (Iyanu ni)

Alagbara giga iyanu ni


Oba Ayeraye (Oba Ayeraye)

Ibere ati opin (Ibere ati opin)

Adeda Aseda (Adeda Aseda)

Olowo gbogboro (Olowo gbogboro)

Eleti lu jara (Eleti lu jara)

Anibi ajere (Anibi ajere)

Eni mimo julo (Eni mimo julo)

Arugbo ojo (Arugbo ojo)

Adagba ma paro oye (Adagba ma paro oye)

Jah Jehovah ni (Jah Jehovah ni)


Iyanu ni iyanu ni (Iyanu ni)

Alagbara giga iyanu ni

Iyanu ni iyanu ni (Iyanu ni)

Alagbara giga iyanu ni

Iyanu ni iyanu ni (Iyanu ni)

Alagbara giga

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status