Aye Yi Nkoja Lo Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2002
Lyrics
Intro
Aye yi ma nkoja lo
Aye yi ma ndogbo lo
Aye yi ma buru si
Omo eniyan etete ronu o
Aye yi ma nkoja lo
Aye yi ma ndogbo lo
Aye yi ma buru si
Omo eniyan etete ronu o
O nkoja lo (O nkoja lo)
O nburu si ojare (O nburu si)
Ah oma ndogbo lo (O ndogbo lo)
Aye yi ma nkoja lo
Aye yi ma ndogbo lo
Aye yi ma buru si
Omo Nigeria etete ronu o
Aye yi ma nkoja lo
Aye yi ma ndogbo lo
Aye yi ma buru si
Omo eniyan etete ronu o
Kilo mohun gbogbo le koko (Ese lo mohun gbogbo le koko) 2x
Otito osi mo iro njoba (Ehn)
Eni afi sole lo tun nfo le (Ehn)
Oba lolori odaran (Ehn)
Apaniyan nrin oyan fanda (Ehn)
Ah laiseni olewi (Ehn)
Ise bo lowo oko (Ehn)
Aya oje kiri (Ehn)
Ewa wole loju popo
Aimoye igba (Aimoye igba)
Aimoye igba se (Aimoye igba)
Ole alaso nwoja
Wonni oba lo ranwon nise
Tani jewi tani jeso
Ni waju odo awon kiniun
Tani jewi tani jeso
Ni waju odo awon kiniun
Toba dara bi oda
Toba dara bi oda o
Olorun esan nwo gbogbo wa
Esan esan esan lonke
Eje alaise nke
Esan esan esan lonke
Eje alaise nke
Toba dara bi oda
Toba dara bi oda o
Olorun esan nwo gbogbo wa
Owo toye ki gbogbo wana kari (Ni wo nikan nko je)
Owo toye ki gbogbo wa ona kari se (Ni wo nikan nko je)
Eke toro ofi palu lara (Nitori iwa re)
Eni ise nse tonwa se (Oni kolo mowo wa)
Ah opo alaini baba (Gbogbo won lon ni lara)
Iwa ibi leyi o iwa ika leyi o
Toba dara bi oda
Toba dara bi oda o
Olorun esan nwo gbogbo wa
Aseyi won won ni
Ase eyin wonni
Aseyi won won ni
Ase eyin wonni
Le njo ba orile ede yi je
Iwo wonni
Ah iwo wonni iwo wonni
Iwo wonni iwo wonni
Le njo ba orile ede yi je
Iwo wonni
Ka gbowo ele kato gbani sise (Iwo wonni) 2x
Kaya alaya to wose ko gba number (Iwo wonni)
Lecturer ton baye omo olomo je (Iwo wonni)
Wey your particulars twenty naira (Iwo wonni)
Ah eleyi oda eleyi oda eleyi oda eleyi oda
Eleyi oye omo Olorun
Instrumental
Eyin olori o etete lo satunse 2x
E satunse o efiwa ese sile
Eyin olori o etete lo satunse
Instrumental
Taba tile ronu o taba tile ronu o (Adara taba tile ronu o)
Taba tile ronu o taba tile ronu o jare (Adara taba tile ronu o)
Aare ronu o gomina eronu o (Adara taba tile ronu o)
Eyin oselu eronu o eyin ologun eronu o (Adara taba tile ronu o)
Pastors ronu o alhaji ronu o jare (Adara taba tile ronu o)
Iwa ote ipaniyan wahala ni gboro ah eje ka ronu (Adara taba tile ronu o)
Nigeria Nigeria Nigeria oye ka ronu (Adara taba tile ronu o)
Oto akoko Nigeria eje kia ronu (Adara taba tile ronu o)
Taba tile ronu o taba tile ronu o (Adara taba tile ronu o)