Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2000

Lyrics

Pharaoah - Evang. Niyi Adedokun

...

Nibi to Iran awon woli ko ba si,

eniyan a yapa o, a si parun o

orile ede ti wolii ko ba ti soro

orile ede yen, nhun be ninu ewu

Oro lori Nigeria ni mo ba wa, gegebi bi alore o mo tun fe ki gbe eee

(string interludes)

1989 ni mo ti nki gbe, nigba ti mo se awo (records) baale mejoo.

isele kan nsele ni nigeria,

oju lasan ko o,,,ara mi gbogbo o.

ileri nkan mbe fori le ede yii o.

ileri isoji nla ki jesu to de.

isoji yen yio si mi gbogbo aye pata,

akoko to le sele, enikan o mo..

ohun ni satani nri,, to si kan lara,

lose gbe pharaoh o dide lati bawa ja,

isale omi ni won si ti fun lagbara

o da eto Oro aje ile yii ru pata

eto iselu nko, o si dori re kodo o

awon to nka iwe gan, o fi sun won

o da orile ede si hilahilo

atohun ati jezebeli aya re,

niwon jo ran nise sorile ede yio

won si nni lati pari gbogbo ise yen

titi di 1995 ara mi

lehin eyi awa gba field marshal

ara hinding agenda ti a nso ni

lai mope olorun orun a da sii

( choruses)

ki e sa se, ki e fo, idajo olorun o

eo lemuje

(interludes)

Mofe ki pharaoh fun ra re tetigbomi

oleje ro lori nigeria

itu toforile ede yi pa o ko gbo

se o ranti majemu ti o besu da

pe wa maa fun leje lososu.

o si npa awon omoogun wa nipakupa

emi toti towore sonu kose so

Yugoslavia,,,,,

Angola a,,,,,,,

sebawon "mogun wa s'onu si b'eyen

siria lone gan k'eniyan dake si ni...

odun keta la'beria ni yi f'gun

seba i'moseye omo ogun wa lo ti lo..

Somalia pelu si nseti re lowo...

olorun l'omoye emi to ti s'onu si

oko ofurufu to jasonu laipe

ti awon major, major fi pare s'onu

ara eje awon tao bere lowo re ni

awon to si nku, iku ojiji won you

eleso pe won lo si course odun mejo.

laimope e ti so iyawo di opo,

laimope e ti so omo di alaini baba


(choruses)

ki e sa, ki e fo idajo olorun oo

eo lemuje.....

(interludes string)

Question

......Your excellency, ,I'm on behalf of national women, we want to know the way you want your sent- forth to be celebrated

Answer

........ get away,

..........are you driving us away?

...........who told you we are going?

........we are not going anywhere

.......don't you know that it's better to die in the white house rather than leaving the white house.

answer

omo queen of the coast to koje,

333 level to wa ninu omi

ohun loje ko fe ku iku olola, state honor

(string and drums)

iwo jezebeli mo fe ki'wo pelu gbo

olejo ro lori nigeria

bere latori akobi re o ti o bi

eyi ti o fiji tori oko tuntun

ara abawon tofi b'orile ede

ohun niwa ipa ti o ngbe kiri

arabinrin ojosi se o ranti

se bara agbode gba iriju re ni

e puro fun wa pe, o ti ku sinu itubu

eni to feso otito yii f'aye

e fi iwe iku ran'ise de torutoru

lgbehin gbehin iriju ko kukuku

beta life,, beta life,,, te fi ntanwaje

kole ran idajo olorun o, lailai

itu tiwo pel'oko forile ede pa

dandan ni ki e gba idajo yin oo

eyin igbimo farao ki e gbo

eyin pelu ni ninu idajo olorun

ohun ti e nje kotile je ki e le soro

dicta-tor o yin tiyin lati se ibi

eyin pelu laju sile e si nwo ran

idajo olorun nduro de yin oo

chrosuses

ki e sa,,, ki e foo ,, idajo olorun oo

e o lemuje

string playing

amoran mi si gbogbo eniyan ni wipe

e je katun bo kun fun adura gidi...

k'ogun abele keji, koma se sele.

mo k'igbe ni 89 lori oro yi

ti gbogbo wa fi gba awe olojo meta

iba si sele ni 1990, nigba tawon eniyan kan fe gba ijoba

satani ko d'eyin lori oro yi oo

o fe d'oju orile ede yi de pata

ti farao ati jezebeli nba nlo

won se tan lati mopo emi dani lo

tori won fe lo opo eje ni 'sale omi

akoko odun won gan an si niyen

kabe olorun orun fun agbara re

oluwa si pawa mo ni gbogbo ona

emi anti-christ o ti wo inu re

emi sise-sise o ti bale laye

tori bayi loluwa awon omoogun wi

bi ati se fun ahabu lojosi

lao o see fun idile farao pata

taya tomo tebi tidile lo njo nlosi

esan ko gbogun o, esan a ke ooo .


+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status