Eniyan Ni Enian A Ma Je Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2008
Lyrics
Eniyan Ni Enian A Ma Je - Evang. Niyi Adedokun
...
Eniyan ni eniyan ama aje
Eniyan ni eniyan ama aje
Biwon kio lowuro, won sinmi le
Biwon kio kasan o, wa ogo re
Eniyan ni eniyan ama aje
Eni tejo kiwo bonu awo jeun tan
Ole joun gan lota oniku Pani
Eni to fokan tan so ashiri re
Ole joun gan ni apani ma Yoda
Eniyan ni eniyan ama aje
Eniyan ni eniyan ama aje
Biwon kio lowuro, won sinmi le
Biwon kio kasan o, wa ogo re
Eniyan ni eniyan ama aje
Eni tejo pinnu papo lati SE is
Ohun gan lotun Dina ati je Mo
Eni to falowo goke to Dara fun
Ohun gan lo duro sibi atako re
Eniyan ni eniyan ama aje
Eniyan ni eniyan ama aje
Biwon kio lowuro, won sinmi le
Biwon kio kasan o, wa ogo re
Eniyan ni eniyan ama aje
Toko ti yawo tiwon pa owo papo
To oko da nikan lo na owo yen je
Eni to ran lowo tun ba o je Kiri
Teni begi loju, igi aruwe dandan
Eniyan ni eniyan ama aje
Eniyan ni eniyan ama aje
Biwon kio lowuro, won sinmi le
Biwon kio kasan o, wa ogo re
Eniyan ni eniyan ama aje
Mama sinmi leniyan iwo oremi
Apani ma Yoda ohun lomo eniyan
Biwon ba rojo re Kiri ni aidara
Mawo ibeyen iwo ni komo ohun toun se
Eniyan ni eniyan ama aje
Eniyan ni eniyan ama aje
Biwon kio lowuro, won sinmi le
Biwon kio kasan o, wa ogo re
Eniyan ni eniyan ama aje
To won ba sope eku irole nbi o
Dakun wa ogo re koto fon esi
Irole won le me agogo meji Lori
Dakun je koju mo koto yo oju siwon
Eniyan ni eniyan ama aje
Eniyan ni eniyan ama aje
Biwon kio lowuro, won sinmi le
Biwon kio kasan o, wa ogo re
Eniyan ni eniyan ama aje