Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2009

Lyrics

[ti:07 Moti Mo Oluwa]


Moti mo oluwa

Oba teni kan ori

Ton ri awa tire

Ton bawa soro

Ni kele kele okan

Ko yipo pada

Oloruko nla

Moti mo oluwa

Oba teni kan ori

Ton ri awa tire

Ton bawa soro

Ni kele kele okan

Ko ma yipo pada

Ko yipo pada

Oloruko nla


Olorun ti soro

Lekan leri keji ni mo gbo pe

Ti oluwa ni agbara lati gbemi

Bori aye

Awon to mo olorun

Awon ni yio sise agbara


Moti mo oluwa

Moti mo oluwa

Oba teni kan ori

Ton ri awa tire

Ton bawa soro

Ni kele kele okan

Ko yipo pada

Oloruko nla


Olorun kan ti ko yipo pada

Loba ti mo ni

Mo dubule ni papa isan omi

Otu okan mi lara

Inu ile re lemi yio ma wa

Titi ojo aye mi


Moti mo oluwa

Moti mo oluwa

Oba teni kan ori

Ton ri awa tire

Ton bawa soro

Ni kele kele okan

Ko yipo pada

Ko yipo pada

Oloruko nla


Ise olorun mi po

E ma si afiwe ogo re

Oba aroni

Nebuchadenezer da oloba nla

Ko ma si atun wi asan

Ninu oro re

Ko le yipo pada


Moti mo oluwa

Moti mo oluwa

Oba teni kan ori

Ton ri awa tire

Ton bawa soro

Ni kele kele okan

Ko yipo pada

Ko yipo pada

Oloruko nla


Olorun mi gbo adura mi

Ma jen waye asan

F’eti anu re gbo ebe mi

Atofarati

Toba le ran mi lowo oba ogo

Ko dun to pari

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo ni o

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Oba to ji oku lazaru dide

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

O le se be

Wa tun se jube lo

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Oba to ni ano loni

To loni to lola

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Koma si iru olorun mi

Ni gbogbo aye

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Oba to ni gbogbo agabra

Ni ikawo

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Olowo gbogboro

Tin yo omo re lo fin

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Alanu

Alaburu ike

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Ani gbogbo aye ni ma

Royin re fun baba

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun


Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

Gbogbo aye ni yio mo

Pe mo l’olorun

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status