- Genre:Gospel
- Year of Release:2009
Lyrics
[ti:05 Nigba Iwase]
Nigba iwase
Tolorun da orun oun aye
Ninu ife o
Pelu omo ati emi mimo
Eniyan lo ba majemu je
Olorun o yidapa o
Baba shin be bi tigba iwase
Nigba iwase
Tolorun da orun oun aye
Ninu ife o
Pelu omo ati emi mimo
Eniyan lo ba majemu je
Olorun o yidapa o
Baba shin be bi tigba iwase
Lati igba atijo
Niwo ti fi ipinle aye sole
Be lo da orun
Enikeni ko shi o nipo
Opo ti o da loti ye kuro
Ninu majemu
Won tele esu
Ti a shi nipo kuro lorun
Opo loti shegbe
Won di egbe bi aso
Ni won paro won
Be ni won o shipo pada
Nigba iwase
Tolorun da orun oun aye
Ninu ife o
Pelu omo ati emi mimo
Eniyan lo ba majemu je
Olorun o yidapa o
Baba shin be bi tigba iwase
Iranti ileri mimo
Ati abraham omo re
Ofayo mu eniyan
Ayan fe re kuro loko eru
O fun won ilea won keferi
Won jogun ere ise won
Sibe won ko pa majemu won
Won se si ofin re
Nitori ayi yipada re
O shey iyonu si won
O mu majemu re se
O ko je ki won pawon run
Nigba iwase
Tolorun da orun oun aye
Ninu ife o
Pelu omo ati emi mimo
Eniyan lo ba majemu je
Olorun o yidapa o
Baba shin be bi tigba iwase
Eniyan to go lo wipe
Bojo tin lo lowo olorun nkuru
Loju won
Owo olorun o kuru
Eniyan lo jino s’olorun
Won jino s’olorun
Won sise irera
Olorun o re ibikan
Eniyan lon je anibi re
Arugbo ojo lolorun wa
Oun loba ayeraye
Nigba iwase
Tolorun da orun oun aye
Ninu ife o
Pelu omo ati emi mimo
Eniyan lo ba majemu je
Olorun o yidapa o
Baba shin be bi tigba iwase
Oun to se laye hannah
Ninu majemu lailai
O tun se be ninu majemu tuntun
Fun elizabeth
Gboggbo agan to woju olorun
Wa di majemu yi mu
Eni ti kin yi pada
Lon yi igba eniyan pada
Nigba iwase
Tolorun da orun oun aye
Ninu ife o
Pelu omo ati emi mimo
Eniyan lo ba majemu je
Olorun o yidapa o
Baba shin be bi tigba iwase
Ife aye yi sha
Eniyan yi okan pada
Afi ife olorun
Nikan nife alayi legbe
Baba fi omo shey owo laye
Iyawo a ma pa oko
Ore to dara si o loni
Le baje si o bo d’ola
Olorun nikan lore otito
Ti kin ye majemu re
Bi isreal ti baje to
Ko je ko parun nitori ileri
Nigba iwase
Tolorun da orun oun aye
Ninu ife o
Pelu omo ati emi mimo
Eniyan lo ba majemu je
Olorun o yidapa o
Baba shin be bi tigba iwase
Aye nyi
Aye ti yi tan
Igba nyi pada
Aye dolo biripo
Aye gbogbo lo
Af’lorun nikan ni ko yi pada
Ife aye
Ife owo
Aye ti yi tan
Igba nyi pada
Aye dogbo lo
Af’olorun nikan ni ko yi pada
Ife kufe ara
Ife kufe oju
Aye ti yi tan
Igba nyi pada
Aye dogbo lo
Af‘olorun nikan ni ko yi pada
Aye n koja lo
Ati ife kufe re
Aye ti yi tan
Igba nyi pada
Aye dogbo lo
Af’olorun nikan ni ko yi pada
Igba ewu ti de o
Aye ti yi tan
Igba nyi pada
Aye dogbo lo
Af’olorun nikan ni ko yi pada