Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2009

Lyrics

[ti:06 Alafia Atayo]


Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu

Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu


Obinrin le gbagbe

Omo omu re

Otile de le ma shey iyonu si

Omo inu re

Sugbon jesu ko je gbagbe

Awa omo re

Owa saye kawa kole ri iye

Lopolopo

Ati ni jesu

Ani olosho aguntan rere


Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu


Aja mo omo tire fun lomu

O mo t’oduoya ki mo le

Awa ti ni ore ofe nla

Aki shey omo aja

Kiniun aya Judea

L’olusho aguntan wa

Jesu ni baba wa

Ati reni to le gba wa


Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu


Opo olusho aguntan aye

Won jun aja ni won je

Won kin yo rara

Beni wok o mo oye

Ono ara won ni won wa

Olukuluku nwa ere re

Won ko ro lati toju aguntan

Jesu ni olusho rere


Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu


Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu


Ajaga jesu fuye

Eru re rorun

Gbo aniyan to

Jesu wa ni o gba o

A ba e le iku lo

A gba o lowo iparun

A fun o niye ayinipekun

Lopolopo


Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu

Alafia atayo

Opo ni jesu mu wa

Kin se baye tin fun ni lalafia

Ti ko layo

Niwon bi ati ni idalare

Nipa ore re

A lalafia pelu olorun

Nipase jesu


Jesu lo le se

Jesu lo le gba o

Lowo gbogbo lasi gbo

Aye yi

Jesu lo le se

Jesu lo le se

Alagbara giga

Jesu lo le gba o

Kinihun eya judea

Lowo gbogbo lasi gbo

Balogun okan wa

Aye yi


Sa to jesu wa

Jesu lo le se

A ba o se tire

Jesu lo le gba o

Oni ewa si odo mi

Lowo gbogbo lasi gbo

Gbogbo eyin to sise

Aye yi


Iwo a di eru wiwo

Le lo ri

Jesu lo le se

Jesu nikan lo le fun o layo re

Jesu lo le gba o

Fi aye re fun

Lowo gbogbo lasi gbo

F’ola re fun

Aye yi

Fi gbogbo idile re fun baba

Jesu lo le se

Un duro lenu ono

Jesu lo le gba o

A ba o pade ni bi isoro re

Lowo gbogbo lasi gbo

Aye yi

Jesu nikan lo le ba o se

Jesu lo le se

Jesu lo le gba o

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status