Odun Nlo Sopin Lyrics
- Genre:Traditional
- Year of Release:1979
Lyrics
Odun Nlo Sopin - C.A.C Good Woman Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin
...
chorus- odun lo so pin o baba rere
baba ma so mi o tomo tomo
oun to yio pa mi lekun o
lodun tuntun ma je ko sele
si was oo baba rere. x2
ma he ka WO leri sunkun
make fi aso ofo bora
ogun roju je roju mu
ma ma je ko je titemi
alafia pipe ni mo fe
fi ta mi lo re je ri na
je ri lo baba wa se mi logo
ma je ta owo na
ma je taraka lodun titun
dabo olorun mi dabo x2
ma je ko win fire the mi
sa pin le( lodun titun)
mama je ko oro mi
ja si ofo lodo re
dabo olorun mi dabo
back to chorus
baba eleruniyi was sire
fun wa ani ka rona gbe GBA
lodun to wole x2
tu won ninu olowa tu won ninu
again ti ko romo gbe pon
tu won ninu oluwa
re won lekun oluwa re won lekun
awon to dabo Hannah rewon
lekun oluwa odo dun no ari orogbo
odo du ni ari Hausa
ki odun ki o San wa si owo
ki odun ki o San wa si owo
ka ri ba tise ki odun yaba
kari on a gbe GBA
ani ki ama to to je
ani ki ama to to mu
ki ama di akisa leyin aso
baba gbo to wa
ka ma se ri Ogun ejo
baba segun aisan
Ogun asedanu Ogun akoba
baba ba wa se abo re to daju
ni awan fe lodun to whole
Ogun rere loye wa baba
fi se wa logo ohun to o pa
wa lekun o ninu odun
ma je ko se le si was
baba rere
back to chorus
odun lo so pin o baba rere
baba ma so mi o tomo tomo
oun to o pa mi lekun o
lodun tuntun ma je ko se le
simi o baba rere