Loading...

Download
  • Genre:Traditional
  • Year of Release:1979

Lyrics

Halleluyah Lo Mu Mi Goke - C.A.C Good Woman Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin

...

Halleluyah lo mu mi goke mo dupę

Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu

Halleluyah lo mu mi goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu mi goke odo

Halleluyah lo mu mi goke mo dupę

Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu

Halleluyah lo mu mi goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu mi goke odo

Ota alôrę, t'o n f'ôrô mi wa lô kiri

Wôn rele adahunse, wôn rele onisegun

Sugbôn ępa ko b'oro mô, wôn p'ete p'ero

wipe k'omi aye gbe wa lô

Igi a ba f'ęyin ti, gbogbo rę ęgun lo ję

Ęni t'ani k'o f'ęni l'oju tun f'ata s'ęnu

Owu kii da k'inu o b'oloko

Gbogbo aja ki p'aja, kikan agbo ki p'agbo ę ję n j'isę Ba mi

Itakun t'o ni k'erin ma goke alô o ti tę

Ôba t'o gbe Mose n'ija, Oun lo mu wa bori

Halleluyah lo mu wa goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu wa goke ayô

Halleluyah lo mu mi goke mo dupę

Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu

Halleluyah lo mu mi goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu mi goke odo

Ninu iwe mimô, awôn t'an ke wôn ti d'asegun

Iwô ke pęlu, wô yo si bori ogun

Ômô Israęli, n'igba ti wôn jade l'oko ęru Mose n ko wôn lô Kenani, n'ilę ileri

Okun pupa niwaju, ogun Farao l'ęyin

Awôn ęlęsin, atawôn ômô-ogun gbiyanju lati ko awôn ômô Israęli l'ęru

Isę Oluwa iyanu ni, iyanu ni

Ôrô Oluwa iyanu ni, iyanu ni

Ôna Oluwa iyanu ni, iyanu ni

Ômô Israęli kôja l'ori iyangbę ilę

Ogun Farao s'egbe s'inu okun pupa

Halleluyah l'orin ayô l'ôjô na

Halleluyah lo mu wôn goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu wôn goke odo

Halleluyah lo mu mi goke mo dupę

Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu

Halleluyah lo mu mi goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu mi goke odo

Oluwa t'o gba Danięli l'ôwô kinihun, ko le s'ai gbô t'emi dandan lati ko mi yô

Oun lo gba Heberu męta 'nu ina ileru

Oun lo gbô ti Jona pęlu latinu ęja

Awôn ęlęri eke dide si mi Oluwa

Iwô t'o gbô t'Elijah, ma s'ai gbô t'emi Baba

Dide Oluwa, se 'dajô f'awôn eke arakunrin

Dide Oluwa, se 'dajô f'awôn eke arabinrin

Iwô to gbe Josęfu n'ija, ba mi d'oju ti wôn l'aye

Ôta n lulu ibaję, Oluwa ni ko ję o dun

Halleluyah ko mu mi goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah ko mu mi goke odo

Halleluyah lo mu mi goke mo dupę

Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu

Halleluyah lo mu mi goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu mi goke odo

Ipinya le de l'aye, sugbôn ayô ni l'ôrun

K'a le jô wa titi pęlu awôn mimô to ti lô

Ipinya le de l'aye, sugbôn ayô ni l'ôrun

K'a le jô wa titi pęlu awôn mimô to ti lô

Halleluyah l'orin ti wôn nkô niwaju Baba


Halleluyah, orin isęgun f'awôn to gbagbô

Paulu, Sila ke ninu tubu ide wôn si ja

Iwô t'ôna rę ba r'uju, iwô t'aye ni l'ara

Halleluyah l'orin tiwa (Halleluyah l'orin tiwa)

Halleluyah l'orin tiwa (Halleluyah l'orin tiwa)

Awôn afôju ke, wôn riran (Halleluyah l'orin tiwa)

Ayarô ke, o fo f'ayô (Halleluyah l'orin tiwa)

Agan ke o si d'ôlômô (Halleluyah l'orin tiwa)

Awôn ôta gbô wôn si sa (Halleluyah l'orin tiwa)

Ogun esu gbô o si sa (Halleluyah l'orin tiwa)

Awôn aję gbô wôn si sa (Halleluyah l'orin tiwa)

Halleluyah lo mu wa d'ęru m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu wa goke odo

Halleluyah lo mu mi goke mo dupę

Halleluyah lo mu mi goke ninu ewu

Halleluyah lo mu mi goke m'awôn ôta lôwô

Halleluyah lo mu mi goke odo

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status