Loading...

Download
  • Genre:Traditional
  • Year of Release:1979

Lyrics

Ara mi yo ya gaga - C.A.C Good Woman Choir, Ibadan. Led By Mrs D.A Fasoyin

...

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

Igbagbõ la fi n rire gba lõwõ Baba

F'igbagbõ rõ m'ęni to le gba õ, arakunrin

F'igbagbõ rõ m'ęni to le gba õ, arabinrin

Gba t'iji aye ba yi lu o, sa gbękęle

Ko gbogbo aniyan rę l'Oluwa, sa ti gbagbõ

Obinrin onisun ęję, to f'igbagbõ tõ Jesu wa nibę lo rire gba

Isun ęję si duro lai t'ori p'o gbagbõ

Ara rę si ya gaga, ara rę si ya gaga

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

Nipa Igbagbõ, Abęli rubõ s'Õlõrun

Nipa igbagbõ, Enõku ba Õlõrun rin

Nipa igbagbõ, Abraham d'õrę Õlõrun

Nipa igbagbõ ni Noha d'olododo

O f'eti si õrõ Õlõrun

N'igba t'o kan õkõ igbala

Ikun omi de, õpõ si s'egbe

Kiki awõn to gbõ ti Noha nikan ni wõn la

Namani f'igbagbõ wę ninu omi, o d'asęgun

Iwõ arakunrin (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

Iwõ arabinrin (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

B'ogun aye ba de (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

B'ogun õta ba de (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

B'o j'owo lo n fę. (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

B'o j'õmõ lo wu õ (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

B'o ję 'le lo fę kõ (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

B'o j'owo lo fę se (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

Iwõ ti ko ri ję (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

Iwõ ti ko ri mu (Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

Agan ma ronu mõ(Sa ti f'igbagbõ rõ m'Oluwa)

Babalawo ko le se

Onisegun ko le se

Adahunse ko le s'õmõ f'igbagbõ rõ m'Oluwa

Ninu Bibeli, Ana f'igbagbõ rõ m'Oluwa

Agan r'õmõ gba t'ori p'o gbagbõ

Õlõrun f'Ana l'õmõ ara rę si ya gaga

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Bi mo ba f'õwõkan isęti asõ rę

Ara mi yio ya gaga, ara mi yio ya gaga

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status