Stay true Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Ṣo stay true to the hustle ni ti o pay
Abi hustle stay true to you men ti o ṣe
Tori that's a two character in a picture
Last time ti mo kọrin fun ẹ kinṣe eboo
Awa dẹ gbe sori o wọ ankara o jẹ sẹmo
Mo n ba ẹ sọrọ ifẹ o loo fẹ ma ro
O da gba igi orogun n gbayẹn nsin ko ma fi ro
This life u go learn ur lesson
Buh lọwọlọwọ u neva learn anything
Nigga face ur fun fact instead ti wa ma fi cap
O un lomumi fi ma da rap lẹnu biti tap
Everytin dẹri balabala buh i gatz to stay sharp
Just wanna make it kodabipe ala ni mo n la
Ti o dẹ ṣe ala ni mo nla ara ni mo kan nda
Bro you look like metro too much o ma jọ metro
Apa ibo loti wa na o da bi awọn ti o ki n soro
Fine boy no pimple kerosine ti o kin sun
Naija lowa taba yọ ijọba ko si issue
Ọbalende lọ si oke sunna wọn ki n sun
Bro you look like metro too much o ma jọ metro
To ba ma order account balance ẹ lo ma lo
Ọro to wa n lẹyi kinṣeteyankan ọrun yabọ
Wọnu aye maammi ẹṣa ma gbadura
Ko sọrọ n bẹ ọpẹlọpẹ lọpẹ satia
Afowomuti ni o ni gbagbe iṣẹ
Ẹni ma san owo ile lo mọ pe kole pẹ