Kosofe Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2023
Lyrics
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinhin kosọfẹ mọ
So me gatz gat wat me want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody ṣo ti ye ẹ kosọfẹ mọ
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinhin kosọfẹ mọ
So u gatz gat wat u want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody ṣo ti ye ẹ kosọfẹ mọ
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinhin kosọfẹ mọ
So me gatz gat wat me want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody ṣo ti ye ẹ kosọfẹ mọ
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinyi kosọfẹ mọ
So u gatz gat wat u want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody ṣo ti ye ẹ kosọfẹ mọ
One plus one equals to two
Lọdọ awọn kan ọmọ oro equals twenty two
Nkanbẹ ko watch wẹgbẹ koto bọlẹ n mile 2
Eyan to baja leeni ole gbọ lọla potiku
Live goes on buh kini ijoba ma bokufa
Just pray for the dead koma lọ jẹ ogun afuka
Astagarulahi lọna times one milli
N ba ni ka durona for like one minute
Buh Iṣẹ yi ma flop awọn ti mo n woyi fẹ turn up
To ba wo instagram ẹ nsin ẹni give up lo fuck up
Don't even com close buh o le kulosa
O ma ma conncur ta wọn niggas n pull over
Nd Y'all been feeelin d flow like pe 2pac padawa
Woju mi korokoro o ma ti n soro soro
Nepa dy show ṣege fuel unkọ e no dy
Ase ma forigbe fowo ajọ ẹ dorime
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinhin kosọfẹ mọ
So me gatz gat wat me want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody ṣo ti ye ẹ kosọfẹ mọ
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinyi kosọfẹ mọ
So u gatz gat wat u want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody ṣo ti ye ẹ kosọfẹ mọ
Kẹma reti sophomore bi ẹni ra loui vuitton
Oko le tan ba summon
Ina Nepa tẹri yẹn yatọ si ti sun mọ
Kodun kopọ kopẹ kotun lẹ
Kosewu loko longẹ giri aparo lo kun bẹ
Kẹlẹsẹ ko mu tẹlẹ ẹsẹ ure lọba tẹ
O dẹ le feṣu ladin kowo nkan to ma dalẹ
O ti da gobe silẹ o ma gobe silẹ o tida gobe silẹ
Owo ti ọmọde ba kọkọ ni afi jakara
O n lodifa fun fabiyi ti o kin fi jakara
Fabiyi na hustler fabiyi tẹramọ ṣẹ
Ko like wahala fine boy ọmọ mama ẹ
O ba fọkan meji si o lo n ma double hustle
Atarọ atọsan atalẹ ko ni sun
ibi to tin ṣiṣẹ wọn ti n wo pẹyẹ wo loṣu
Ifa to da fun yin yatọ ẹ dide tabi kẹ sun
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinhin kosọfẹ mọ
So me gatz gat wat me want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody o ti ye ẹ kosọfẹ mọ
Igboro ti jẹ ko ye wa pe kosọfẹ mọ
A dẹti n foju ri nisinyi kosọfẹ mọ
So u gatz gat wat u want kosọfẹ mọ
Ole ni everybody o ti ye ẹ kosọfẹ mọ