Loading...

Download
  • Genre:Others
  • Year of Release:2023

Lyrics

Malọ ma ṣa farawe

Lo mọwe

Malọ ma ṣa farawe

Kole si holiday ye ye ye


Wa ọmọ ọpẹ nothing goes for free

Kilago sọ oni 2:30

Ṣiṣẹ mọju kin le sun to ba ti 6:30

O di 10:30 kalọ agbo Dj 4kerty

A wa o gbọmọ wa a ma gbọmọ lọ o ti sure ju

Every situation mo barami I been grateful

Ọlọpa dami duro mo bere kini issue

Amuludun ni mi officer ẹ mani reṣu


Awe malọ ma ṣa farawe

Ẹni to mọ way lo mọwe

Ojojumọ la fi n ṣiṣẹ ko si holiday ye ye ye

Awe malọ ma ṣa farawe

Ẹni to mọ way lo mọwe

Ojojumọ la fi n ṣiṣẹ ko si holiday ye ye ye



Ko le si holiday ko le si holiday o

Kin ma bere 2k kiri ko le pọnmile o

Ọkan a ti balẹ ju ti mi o ba sanle o

Olokọọ tuntun o le pe mi ni sanle o

Ko duro soke jẹ ko wa lẹ

Ogiri leti eyan lo n jẹ bẹ

Oluwa ni Greatest ohun ni d highest

Anybody can be richest in any aspect

O tun le useless in any aspect

Yeah i'm trynna learn iyẹn from d realest

Kin ma kan ẹ komakan ẹ ni ifun lọ deepest

Owo ni love language ti mo ni interest

Alangba to dakun delẹ pọ a mọyi tinu n run

Trap la n jẹ ẹyin lo n bere fun new tune

Now on a new tune tori ọpọn ti n sun

OMG ki lo ṣẹlẹ si Virgil


Ọmọ ọpẹ nothing goes for free

Kilago sọ oni 2:30

Ṣiṣẹ mọju kin le sun to ba ti 6:30

O di 10:30 kalọ agbo Dj 4kerty

A wa o gbọmọ wa a ma gbọmọ lọ o ti sure ju

Every situation mo ba ra mi I been grateful

Ọlọpa dami duro mo bere kini issue

Amuludun ni mi officer ẹ mani reṣu


Awe malọ ma ṣa farawe

Ẹni to mọ way lo mọwe

Ojojumọ la fi n ṣiṣẹ ko si holiday ye ye ye

Awe malọ ma ṣa farawe

Ẹni to mọ way lo mọwe

Ojojumọ la fi n ṣiṣẹ ko si holiday ye ye ye



Malọ ma ṣa farawe

Lo mọwe

Kole si holiday ye ye ye

Malọ ma ṣa farawe

Lo mọwe

Kole si holiday ye ye ye


Ko le si holiday ko le si holiday o

Kin ma bere 2k kiri ko le pọnmile o

Ọkan a ti balẹ ju ti mi o ba sanle o


Kole si holiday ye ye ye

Malọ ma ṣa farawe

Lo mọwe

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status