Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2016

Lyrics

Satani Kanjangbon - Pst. J. A. Adelakun

...

Instrumental

Baba wa mbọ o

Jésù mbo kọ́ni pẹ́ de mọ

Alágbára mbo Jésù wá mbọ wa

Jésù wá mbọ láti wá ṣèdájọ́ aye

JÉSÙ mbọ kò nipẹ de mọ

JÉSÙ mbọ kò nipẹ de mọ

Gbogbo ojú ni yio ri

Àtàwọn to kan Jésù mọ'gi

Jésù mbọ kọ́ni pẹ de mọ

Alágbára mbọ Jésù wá mbọ wa

Jésù wá mbọ láti wá ṣèdájọ́ aye

(Instrumental)

Ti Jésù bá dé, sátánì yio fèrè ge

Ti Jésù bá dé, sátánì yio dàwátì o

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó dà 'ran

Torí Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajo aye

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó kẹ 'ran

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó dà 'ran

Torí Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajo aye

(Instrumental)

Ọjọ́ tí pẹ ó t' otin dá lé ayé ru

Ọjọ́ tí pẹ ó t' otin bale ayé jẹ

Ká f'ọmọ lọmọ ṣẹ 'ṣó ìṣe ọwọ rẹ ni (bẹni)

Ká d'eniyan ni gbèkùn ìṣe ọwọ rẹ ni

Ẹni tó fẹ́ ṣe' fẹ Jésù ìwọ lóde wọn l'ona

Odaju, sátánì a jí 'yà ó ti Jésù bá dé

Sátánì kan jọgbọ́n ó kan'jogbọn mo lo ru' gi oyin

Torí Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajo aye

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó kẹ 'ran

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó dà 'ran

Torí Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajo aye

(Instrumental)

Gbogbo ayanfẹ o ẹ múra silẹ ó

Ẹyin ayanfẹ ó ẹ múra de Baba o

Eyin ayanfẹ o ẹ jọ̀wọ́ ẹ múra silẹ ó

Gbogbo ayanfẹ ó ẹ múra de Baba o

Laipe ọjọ tao mo Baba wa yio yọ

Lawọ ṣanmọ o nio tí yọ pẹ̀lú àwọn ogún ọrùn tó ń kọọ mimọ mimọ

Ẹyin ayanfẹ torí na ẹ múra silẹ o

Sátánì kanjọgbọn ó ti Jésù bá de

Sátánì a jìyà ó ti Jésù bá de

Torí Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajọ aye

Ọkàn 'jọgbọ́n o

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó kẹ 'ran

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó dà 'ran

Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajo aye

O fẹrẹ de o

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó kẹ 'ran

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó dà 'ran

Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajo aye

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó kẹ 'ran

Sátánì kanjọgbọn ó kanjọgbọn ó dà 'ran

Jésù wá mbọ láti wá ṣe dajo aye

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status