Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2014

Lyrics

Ibanuje Ti Keru - Pst. J. A. Adelakun

...

Ibanuje ti keru oṣi mari lò 2x

Oke ìṣòro mi tí dipetele ipọnju tilọ

Ọlọrun alagbara ọba tí kìí ba ti oun lo pabanuje ayé mi rẹ, 2x

Ibanuje ayé mi gbogbo relo tito lo, ìṣòro ayé mi gbogbo relo tìwo,

Awọn ogún orun ní won sokale, wọn rún wón womuwomu, ina to sokale latorun óò ojowon raurau ojowon pátápátá, ibanuje ti jóná ipọnju ti jóná idamu tì jóná agbana ti jóná aṣedanu ti jóná wàhálà ti jóná amubo ti jóná, moranti iku òjìji Jesu losegun fún mi pátápátá,

Ibanuje ti keru oṣi mari lò 2x

Oke ìṣòro mi tí dipetele ipọnju tilọ,

Ọlọrun alagbara ọba tí kìí ba ti oun lo pabanuje ayé mi rẹ, 2x

kini ibanuje rè tete waso fún Jésù ohùn to'n daọ lọkàn ru óò kosoro f'oluwa 2x

Botiwu kogun ayé lè to, botiwu kisorori, botuiwu kesu gbogun to botiwu k'ayé dide to, to ba gbajesu gbọ ọrọ itan ni isoro adá lọla, b'ekun pe dálé kan o ayo n bọ l'owurọ

Ibanuje ti keru oṣi mari lò 2x

Oke ìṣòro mi tí dipetele ipọnju tilọ

Ọlọrun alagbara ọba tí kìí ba ti oun lo pabanuje ayé mi rẹ, 2x.

Agbara Ọlọrun wà kìí bati óò

rararara 2x

Agbara baba mi kìí ba tio

rararara

Agbara to'n j'oku dìde kìí ba ti

rararara

Agbára to'n laju afọju kìí ba ti o

rararara

Agbára to'n Segun oso kìí ba ti

rararara

Agbara to'n pajẹ́ lenu mọ kí mai báti

rararara

Agbara to'n s'agan dọlọmọ kìí ba ti lonje

kìí ba ti

Agbara to'n munun eni dun kìí ba ti lonje

kìí ba ti

Onjade ontude molon tunwa sọrọ ẹni dayọ

iyanu Ni 2x

Agbara baba wá agbara ti kìí ba ti o

rararara

Agbara agbara agbara ti kìí bà tio

rararara

agbara to'n segun fún ni kìí ba ti lonje

kìí ba ti

Agbara to'n gbagbe eṣu kìí ba ti lonje

kìí ba ti

Agbara baba mi agbara jesu kima ìí ba ti

rararara

Onjade ontude molon tunwa sọrọ ẹni dayọ

iyanu Ni 2x

Iyanu iyanu agbara baba mi kìí ba ti o

rararara

Agbara baba mi agbara jesu kìma ìí ba ti o

rararara

Agbara agbara agbara baba mi kìí bà tio

rararara

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status