Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2016

Lyrics

Amona Tete M Bo - Pst. J. A. Adelakun

...

Amona o

Amona tete wa o, amona tete bo

Amona tete wa o, amona tete bo (Tori pe)

Aye n ba je o, amona tete bo

Aye n daru o, amona tete bo


Jesu Kiristi l'amona

Oun lo le tun le aye wa se

A n reti re o Baba, a fe r'oju re

Igba ti Jesu ba de, l'aye yi to le toro o

Igba ti Jesu ba de, l'aye yi to le dara

Ikiri lojojumo, nise lofin gori ofin

sibe sibe ara mi gbogbo, aye o fi be toro

Ologun n be lode, aye n rojo kiri

Oselu tun tun wo be o, igbe laraye nke

oselu to koja lo, ejo laye n ro

Ologun lo tun wobe o, Igbe laraye n ke

Otito o nile mo, iro laraye n fe

Ododo o ri bi gba o, ese ti bori aye

Afi ti Jesu ba de, laye yi to le toro

Afi ti Jesu ba de, laye yii to le dara

Amona tete ma bo o, amona tete ma bo wa

Aye n daru lo o, ese n gori ese lojojumo

Aye ma dobiripo, amona tete


Amona o


Amona tete wa o, amona tete bo (amona o)

Amona tete wa o, amona tete bo (nitori pe)

Aye n ba je o, amona tete bo

Aye n daru o, amona tete bo


Oun tiwe mimo wi, gbogbo re lo ti n se

Oro ti Jesu wa so, gbogbo re lo n f'ara han o

Ta ba wonu aye, a o ri p'aye n dogbo lo

Orile ede n dide sira won, ogun at'ote nsele

Mo l'ogun n'ile, ogun n'ile, ogun l'oko

Wahala aye yi ma poju, alagbawi tete ma bo

Mo ni laye atijo, oun gbogbo n lo dede

Ojo n ro lasiko re, orun n yo lasiko re

Osupa n yo lasiko re o, Oye n mu lasiko re o

Isu n jade lasiko re o, agbado n jade lasiko re o

Mo ni la o f'orogun, oun gbogbo n lo dede

Olaju olaju

Olaju lo de lo b'aye je

Awon to n s'olori wa, okanjua lo poju o

Dugbe dugbe kan n fi

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status