- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Ire Iran - Adeyinka Alaseyori
...
awọn kan ku láìsí imuse ileri
ọlọrun mio fe
awọn kan fetí gbo ileri titititi sugbon ko pada se oloun
ìlérí ti mogbo ninu Bibeli at'ẹyi ti mola loju ala,eyi ti mori ninu iran ati isọtẹlẹ ire ire ire iran mio o tete se lori mi tete se majenku kogo otọde o
ire iran semon mi lara iran ire jo ṣe monmilara o ireiran iran ire tete se
pataki pataki ni wipe imuse ileri akaimonye ileri táti fetí gbo tio ba imuse pade o
ìdádúró ileri ìdádúró ala tabi iran olemu komo ologo ma rare ọ akoko imuse ìlérí otọ ire iran ṣe monmi lara gbogbo idile loni ire iran atiibi iran eeha t'ise toje wipe Egun iran lon tele opolopo kiri ire iran mi da oo akoko imuse to ọ
ọlọrun awọn timo f'oro lo tosa ogo mi logbe awọn timo gbarale toje pe Egun nafi sara awọn timo so iran fún tiwon ri iran kinto ri tiwon transform e tiwon exchange e fomo won tabi ese mi,aṣiṣe mi,ese iran mi,ese awọn obi mi ese ibi timogbe,ile timoko,ibi ti motin taja gbogbo ese tole mada imuse iran duro ọlọrun dariji mi o
ọlọrun wọn lo man dahun adua oo
ọlọrun oma ndahun adua o imuse ileri mi dao imuse ileri mi dao
see lyrics >>Similar Songs
More from Adeyinka Alaseyori
Listen to Adeyinka Alaseyori Ire Iran MP3 song. Ire Iran song from album Ire Iran is released in 2021. The duration of song is 00:09:08. The song is sung by Adeyinka Alaseyori.
Related Tags: Ire Iran, Ire Iran song, Ire Iran MP3 song, Ire Iran MP3, download Ire Iran song, Ire Iran song, Ire Iran Ire Iran song, Ire Iran song by Adeyinka Alaseyori, Ire Iran song download, download Ire Iran MP3 song
Comments (218)
New Comments(218)
Oyekan Yemmith
adejoke2jn5y
ire iran jo se mo mi laraa
Suleiman Ikeade
God bless me and my husband and change our life's to good Amen
Suleiman Ikeade
thank you Lord for forgiven my sins
Taiwo Olatian
i love it
Mercyvxw1g
Good song with meaningful
Peace2mxdy
Melodious and impactful
Robert 5wjj6
If you have zenith Bank account that can take up to 50,000,000 naira you drop for Online cheque deposit .. I have a direct zenith log tools now Please and please the account needed is account that has a good transaction history account that have run transaction of millions for the past month I'm ready for job 2/4/7 Don't give me small children zenith Bank account.. don't give me new account within 5 hours time the job is done +2347036681271
Spiritual things
Good morning
Spiritual things
Hi
Ausjames
nice one
Temitope22 qdncg
beautiful
ma'am you're the lord choosing one.. your songs makes me cry some times when listening to it.. it's inspirational.. you will long ma..aye oni fi owo bo ogo yin ati awon yin loruko jesu.to ba to akoko ati jere ise owo yin ao ni fiyin sa awa ti AMEN
Amen Amen in Jesus Christ name