Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2021

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Ire Iran - Adeyinka Alaseyori

...

awọn kan ku láìsí imuse ileri

ọlọrun mio fe

awọn kan fetí gbo ileri titititi sugbon ko pada se oloun

ìlérí ti mogbo ninu Bibeli at'ẹyi ti mola loju ala,eyi ti mori ninu iran ati isọtẹlẹ ire ire ire iran mio o tete se lori mi tete se majenku kogo otọde o

ire iran semon mi lara iran ire jo ṣe monmilara o ireiran iran ire tete se

pataki pataki ni wipe imuse ileri akaimonye ileri táti fetí gbo tio ba imuse pade o

ìdádúró ileri ìdádúró ala tabi iran olemu komo ologo ma rare ọ akoko imuse ìlérí otọ ire iran ṣe monmi lara gbogbo idile loni ire iran atiibi iran eeha t'ise toje wipe Egun iran lon tele opolopo kiri ire iran mi da oo akoko imuse to ọ

ọlọrun awọn timo f'oro lo tosa ogo mi logbe awọn timo gbarale toje pe Egun nafi sara awọn timo so iran fún tiwon ri iran kinto ri tiwon transform e tiwon exchange e fomo won tabi ese mi,aṣiṣe mi,ese iran mi,ese awọn obi mi ese ibi timogbe,ile timoko,ibi ti motin taja gbogbo ese tole mada imuse iran duro ọlọrun dariji mi o

ọlọrun wọn lo man dahun adua oo

ọlọrun oma ndahun adua o imuse ileri mi dao imuse ileri mi dao

melo nigba to ti gbo poma travel owo local flight ri

ọpọlọpọ deti rin irin ajo ogo lolu ọba ṣugbọn sibẹsibẹ imuse ileri otise melo nigba to ti gbo póma loyun? oyun kan oduro rí imuse ìlérí lonilo o melomelo ni awọn ọdọ ton láwọn l'ogo toma gbe ilega atorile ede àwọn nan rare kiri imuse imuse ire iran da o

àìmọye ebe ikoko toni t'iwo funrararẹ damon to nilo imuse le lori mutie ko bere sini bẹrẹ imuse bere imuse ileri ogo

àìmọye awọn ọmọ to monwe teletele sugbon t'ayé pa kadara won da lojiji, omo toje akíkanjú tomowe gidi ọwá dẹni tón seru labẹ ẹrọ

iwo na bere fún imuse ileri bere fún imuse ileri

iṣẹ tonse yẹn lopolopo la tiwon fiyan tiwon fiyanju Logan to dawole gbogbo rẹ dojude kilode?imuse ìlérí lonilo óò otinse fún ọdún modun osu mosu to'lorun lọ fún imuse ileri àní agbejo ro nla jéésù loruko re o

ogo ogbudo bami n'iboji èèwò mini imuse ire iran kogbudo bami Logba were eewọ mini akoko to lati dide lori oro mi oluwa dide iree iree ire iran mi o tete se lori mi tete se majenku kogo otọ dé óò ire iran ṣemon mi lara iran ire jo ṣemon mi lara óò ire iran,iran ire tete se

ẹrí mi ogbudo bami ni iboji o ẹrí mi ogbudo bami ni iboji o igba togo bade emi mi ogbudo pin lojiji ẹrí ogbudo bami ni iboji o oti Lola ri lokola mọn ko kinse ipin mi o eyin te hun duro lati ja mibo lojiji Ema duro lasan eyin ten reti ojo temagbo iku mi,iku omo ,iku oko,èmi ni ma f'eru f'eru yín àti iyepe fún iyepe yin eo ni rerin kehin lori oro mi ẹrí oni bami n'iboji o

awọn ton womi loke ton fe kin Jabo awọn ton reti ipada bo olowo sí talaka lori mi ewo ni ẹrí gbo nigbati imuse bade ogbudo bami n'iboji óò ti ẹrí bade tan ti iran lọwọ bade ti igbe dide bade ati idahun adua wọn oni fimi pitan ogo wọn oni fimi pitan búburú ninu ogo ẹrí ẹrí ogbudo bami n'iboji óò

ologo lowo niku bade k'isẹ ipin re awọn ọmọ to mo ṣe fún e je wón oni da emi won legbodo lojiji lori oro re ogo to'lorun fi tao lore oni fowo re gbọmọ sìn ọ ẹrí ogbudo bami n'iboji nigba tẹri bade tan ti ogo bade tan halleluyah lorin mi halleluyah ni orin mi halleluyah koni tan lenu mi sí o óò iwo t'ogba kile mi o dahoro titi lailai halleluyah lorin mi sí o nho ma korin wipe igba kan ri mọn tọrọ jẹ ìgbà kan ri mọn f'ogo rare ọjọ ti moti mọn p'olodumare laye mi yipada igba mi d'ọtun ninu re lojo ti mo timon p'olodumare laye mi yipada sí rere

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status