Ise T'Olugbala Ran Mi
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2001
Lyrics
Ise T'Olugbala Ran Mi - Evang. Niyi Adedokun
...
Ise t'olugbala ran-an mi aajeye ni ngo je Ise tolugbala ran-an mi aajeye ni ngo jee ....... Botiwu k'ogun Ota dide Botiwu k'ogun esu dide Laarin awon eke arakunrin Laarin ogun awon agbeni pa Ise t'olugbala ran-an mi aajeye ni ngo je Ise tolugbala ran-an mi aajeye ni ngo jee ......... Egbo ikede pataki gbogbo eniyan Okiki ti kan siwa sehin wipe motiku Pelu agbara Olorun mo si wa laaye Bi Ko Ba tiito akoko to lorun da funmi Nipa Ifè olugbala kole si nkan Ise t'olugbalaIse ran-an mi aajeye ni ngo je Ise tolugbala ran-an mi aajeye ni ngo jee ......... Gbogbo eyin Ayanfe olorun Nibikibi ti e Ba ti ngbo Orin mi Ema gbadura funmi tosan toru Àti lopin irin ajo mi laye Kin nsinmi lodo Jesu oluwa Ise t'olugbala ran-an mi aajeye ni ngo je Ise tolugbala ran-an mi aajeye ni ngo jee
Similar Songs
More from Evang. Niyi Adedokun
Listen to Evang. Niyi Adedokun Ise T'Olugbala Ran Mi MP3 song. Ise T'Olugbala Ran Mi song from album Mr. Awayemalo 2 is released in 2001. The duration of song is 00:03:10. The song is sung by Evang. Niyi Adedokun.
Related Tags: Ise T'Olugbala Ran Mi, Ise T'Olugbala Ran Mi song, Ise T'Olugbala Ran Mi MP3 song, Ise T'Olugbala Ran Mi MP3, download Ise T'Olugbala Ran Mi song, Ise T'Olugbala Ran Mi song, Mr. Awayemalo 2 Ise T'Olugbala Ran Mi song, Ise T'Olugbala Ran Mi song by Evang. Niyi Adedokun, Ise T'Olugbala Ran Mi song download, download Ise T'Olugbala Ran Mi MP3 song