Loading...

Download
  • Genre:Afropop
  • Year of Release:2021

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Àkọ́kọ́ - Brymo

...

èmi ni

èmi lẹni náà

Ọkùnrin mẹta at'aabọ tán forin bọ

èmi ni

èmi l'ọmo naa

Ọkùnrin merin at'aabọ won n t'ẹnu mọ

mo laanu mo sọrọ

mo yọ aake mo fọ ọrọ

ọmo ọlọfọọrọ

mo jẹ àkara ọfọọrọ

èmi ni Hàáà!

èmi ni hoo!

èmi máa lẹni tan sọ n'igboro

èmi ni yaa

èmi ni yóò

awọn mama gan soro ni pópó

wọn lè mi láàkọ́kọ́

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo

èmi ni Ọkùnrin náà,

t'awon majesin n so pe o m'orin gaan

èmi ni, èmi l'ọmo náà,

Gbogbo ará àdúgbò lon t'ẹnu mọ

èmi baba olowo

mo ṣe owo mo jeere

iwa ati ọpọlọ lo n lo

awọn ọta ti ru pò

èmi ni hàáà!

èmi ni hooo!

èmi máa lẹni tan sọ n'igboro

èmi ni yaa

èmi ni yóò

aawọn ọmọge n rodi ni pópó

wọn lè mi láàkọ́kọ́ (iwo láàkọ́kọ́)

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo (iwo láàkọ́kọ́)

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo (iwo láàkọ́kọ́)

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo (iwo láàkọ́kọ́)

wọn lè mi láàkọ́kọ́ (iwo láàkọ́kọ́)

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo (iwo láàkọ́kọ́)

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo (iwo láàkọ́kọ́)

wọn le mi láàkọ́kọ́ ooo (iwo láàkọ́kọ́)


Lyrics Added by MedalProse

follow me on Boomplay, BoomBuzz and Boomsing

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status