Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:1987

Lyrics

Opin Aiye - Dupe Olulana

...

Òpin aiyé súnmó etílé,

Onígbàgbó lo múra,

Kábamò má ba jé tìre,

Gbàtí Jèsú bádé,

Ko lè gbadé aláyò ní Jerúsálèm t'òrun. Ìhìnrere ti Jòhánnù nkó gbogbo onígbàgbó pé,

Ká sisé lówurò,

Nítorí òru súnmólé,

Òru n bòwá o,

Tí a kò mà ní lè sisé.

Awaiyé móyà ko lo mò wípé,

Aiyé yìí kì se tìre,

ìIú ìbílè wa tó wà l'òrun,

Ní àwa yóò ti pàdé,

Lójó tí ìpè bá dún ò,

L'àsírí elésè á tú.

Òpin aiyé súnmó etílé, Onígbàgbó lo múra, Kábamò má ba jé tìre, Gbàtí Jèsú bádé, Ko lè gbadé aláyò ní Jerúsálèm t'òrun.

Alágbèrè óse nítorí ojó ìdájó dé o,

Ojú àgbèrè kò lè rí Jésù Ko má se gbàgbé,

A ó gbà ó là tí o bá ronú wò Tó sì rántí pé,

Ojú tí kìí désè ní yóò bá Jésù wolé.

Èyin tí n segbé òkùnkùn,

Àt' èyin olùse búburú,

Àánú Olúwa n rò yín pé E fòkùnkùn sílè,

Torí bí Jésù bá dé lòjijì Èpa kò ní bóró,

Ò bá ronú re wò Ko yípadà kí Jésù kótódé.

Òpin aiyé súnmó etílé, Onígbàgbó lo múra, Kábamò má ba jé tìre, Gbàtí Jèsú bádé, Ko lè gbadé aláyò ní Jerúsálèm t'òrun.

Jésù Olúwa nbò kánkán, Láti pín èrè isé wa, Isé to bá se nílé Olórun Á jèrí tì ó, Ojú j'ojú kò sí lódò Jésù, E má bà gbàgbó jé o.

Òpin aiyé súnmó etílé, Onígbàgbó lo múra, Kábamò má ba jé tìre, Gbàtí Jèsú bádé, Ko lè gbadé aláyò ní Jerúsálèm t'òrun.

Òpin aiyé súnmó etílé, Onígbàgbó lo múra, Kábamò má ba jé tìre, Gbàtí Jèsú bádé, Ko lè gbadé aláyò ní Jerúsálèm t'òrun.

Òpin aiyé súnmó etílé, Onígbàgbó lo múra, Kábamò má ba jé tìre, Gbàtí Jèsú bádé, Ko lè gbadé aláyò ní Jerúsálèm t'òrun.

Òpin aiyé súnmó etílé, Onígbàgbó lo múra, Kábamò má ba jé tìre, Gbàtí Jèsú bádé, Ko lè gbadé aláyò ní Jerúsálèm t'òrun.

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status