Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:1993

Lyrics

Adura Mi - Dupe Olulana

...

Adura mi oo

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

Adura mi oo

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

Ibere ki s’onise

Ibere ki s’onise rara

Eni to ba d’ori ti d’opin la o gbala oo

Jesu je kin le s’aseyori

Ire ije ti mo nsa

Ire ije ti mo nsa baba

Oluwa ma je kin jin sofin laye

Je k’emi le de ikon ba re

Adura mi oo

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

Baba ma je kin nsiyemeji

Baba ma je kin nsiyemeji oo

Oniye meji ko ma ni jogun Ijoba re

Yio pare mo aye lara ni

Ife owo npa ni lara ye

Ife aye nsi ni lona jojo

Je ki nle ma wa ijoba olorun laye

Ati ododo re

Adura mi oo

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

Ohun gbogbo yoo ma tele mi

Ire gbogbo yoo ma tele mi (ire owo)

Ire gbogbo yoo ma tele mi (ire Omo)

Ire gbogbo yoo ma tele mi (Alafia)

Je ki nle ma wa ijoba olorun laye

Ati ododo re

Adura mi oo

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

Igboran lo ngbe ni dele ogo

Ki ise nipa ise owo wa nikan

Igboran lo ngbe ni de odo baba

Ki ise nipa ise owo wa

Oluwa yo so fun awon alaigboran pe

“Mi o mo yin ri, eyin onise ese;

Ekuro Lodo mi, Ema lo sinu ina”

Oluwa yo so fun awon alaigboran pe

“Mi o mo yin ri, eyin onise ese;

Ekuro Lodi mi, Ema lo sinu ina”

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

Ohun gbogbo yoo ma tele mi

Ire gbogbo yoo ma tele mi (ire owo)

Ire Omo yo ma tele mi

Alafia yo ma tele mi

Je ki nle ma wa ijoba olorun laye

Ati ododo re

Adura mi oo

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

Adura mi oo

Adura mi lojojumo

L’owuro l’osan at ‘asale

Nigba kugba, nibi kibi ti mo wa laye

Baba Ma pa mi ti

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status