O Fun Mi L'edidi (He Gave Me the Seal of Redemption) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2013
Lyrics
O Fun Mi L'edidi (He Gave Me the Seal of Redemption) - Tolu Akande
...
O fun mi l'edidi,
'Gbese nla ti mo je,
B'o ti fun mi, o si rerin,
Pe, “Mase gbagbe mi!”
O fun mi l'edidi,
o san igbese na;
B'o ti fun mi, o si rerin,
Wi pé, “Ma ranti mi!”
N ó p'edidi na mo,
B'igbese tile tan;
o n so ife eni t'o san,
Igbese naa fun mi.
Mo wo, mo si rerin
Mo tun wo, mo sokun;
eri ife Re si mi ni,
N ó toju re titi.
Ki tun s'edidi mo,
Sugbon iranti ni!
Pe gbogbo igbese mi ni,
Emmanueli san.