Sure Fun Wa L'oni Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Sure Fun Wa L'oni - Tolu Akande
...
SURE fun wa loni, Baba wa orun
A gboju wa soke si O,
Wo to sure f’Abraham
baba wa,
Jowo sure fun wa.
Egbe: Alpha ati Omega
A si okan wa paya fun O,
Ma je ka lo Iofo.
2. Metalokan Mimo Alagbara
Ife to jinle julo
Awamaridi Olodumare
Jo f’ire kari wa.
Egbe: Alpha ati Omega
A si plan wa pays fun ò
Ma je ka lo lofo.
3. Awa nke pe O loni, Baba wa,
Ma je k’omo Re rahun
Ko sohun ti jamo lehin ekun
Jowo dabobo wa.
Egbe: Alpha ati Omega
A si okan wa paya si Olodumare
Ma je ka lo lofo.
4. Wo lo m’omi lat’inu apata
F’awon enia Re saju
O rojo manna pelu lat’orun
Jowo pese fun wa.
Egbe: Alpha ati Omega
A si okan wa paya fun O,
Ma je ka lo Iofo. Amin