Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2020

This song is not currently available in your region.

Lyrics

Omo Opé ft. Dotman - Seriki

...

Olole olole

Orí mi ò ogbabode

Ọjọ́ tebi ń pale

Orí mi ò sì nílé

Owó mi ò ní pe de

To rí ẹ mi ó fọ faye

Ope mi ò mo moore

Ẹsẹ̀ Dákun má sina

Níbi orí ń gbé mi lọ

Baba má je ko jìnà o

Kí dùn nù yẹn kò popopo kò po

We gó dey parte After parte

Rale after rale

E wo àwọn ọmọ ọpẹ bo se n jaye

Baba ti ṣe wọn rowo fi se

Kí lóde tí ẹ fe bá mi ja

Ṣe é mo pe èmi fún ara miAbija

Mi ò ráyè Talk tó my manager

Mo fẹ́ lowo bí Folorunsho Alakija

Kí ni mo ra nígbà wọn

O ti sú mi o

Kí lóde tẹ fi ń wá ìṣubú mi

Binu bínú máa bínu kú ni

Mo gbé wípé popsi mi

Mo ti jiya seyin

Ọmọ so tí rántí

A ń sílè everyday bí ẹni tó ń soti

Séríkí ọmọ owó mi ò kí n fò fún somori

Àwọn somori gan kò lè rí í kí wọn làwọn ó mọyan rí

Mr. Bunbasi Mr. Fantastic

MO wà romantic

Fun mi Lomo tó lọ ú ńlá bí Dorothy

Ẹsẹ̀ Dákun má sina

Níbi orí ń gbé mi lọ

Baba má je ko jìnà o

Kí dùn nù yẹn kò popopo kò po

We gó dey parte After parte

Rale after rale

E wo àwọn ọmọ ọpẹ bo se n jaye

Baba ti ṣe wọn rowo fi se

Séríkí ó.. Kúrò nbeyen na

Dotman.. Kúrò ńbeyen na

Waja.. Àwọn somori. Kúrò nbeyen na

Séríkí ó wale

Ọmọ oro ó yojo

Mo ti gba lowo ẹ torí mo rí wipé kò mọọ lo

Mo yọnu yeke bí ti Oga Bello

Orí ẹ ó fero

Ìṣe tó ti tà kò need ìpolówó

Ọmọdé olowo

Everybody mo Fadeyi Oloro

Kò dìgbà tí Fadeyi bá báwọn gbé egbògi oloro

A ń ná pounds kilowa ń be

A ń ná dollars kílowa ń be

To bá wo'sale Sokoto mi ẹrú wá nbe

Tí Mo Bá ra vasace mo má bá orí Medusa nbe

Orí mi ò ogbabode

Ọjọ́ tebi ń pale

Orí mi ò sì nílé

Owó mi ò ní pe de

To rí ẹ mi ó fọ faye

Ope mi ò mo moore

Ẹsẹ̀ Dákun má sina

Níbi orí ń gbé mi lọ

Baba má je ko jìnà o

Kí dùn nù yẹn kò popopo kò po

We gó dey parte After parte

Rale after rale

E wo àwọn ọmọ ọpẹ bo se n jaye

Baba ti ṣe wọn rowo fi se

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status