Loading...

Download
  • Genre:Fuji
  • Year of Release:2020

Lyrics

Adé Orí Òkin - K1 De Ultimate

...

Ayinde ogun, beyan ba nyole da ohun burúkú a mmá yo'ru won ṣe

mmo I so teletele ninu orin to rẹ k'oja

ẹni Olohun nfe l'omo eyan nfẹ

e ma y'onu simi

agba ati omode e ma y'onu simi óò

okunrin t'obinrin e y'onu simi

ẹni nba y'onu simi

sure ju

ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba, oun le o máa ríi.

moni é má y'onu simi

okunrin e y'onu simi

Obìnrin è y'onu simi

gbogbo ẹni ba n'yonu simi

o sure ju

ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba, ìyọnu ọlọhun ọba,

oun le o ma ri

aanu mo ri gba, ade ori okin

aanu mo ri gba, ade ori okin

èmi njaye ori mi

ade ori okin

ki dé nṣe mímọ ṣe

ade ori okin

ki má ṣe nṣe mímọ ṣe

ade ori okin

aanu mo ri gba, ade ori okin

ọmọ aládé alafia

ade ori okin

Ayinde, ọmọ aládé alafia

ade ori okin

ìran eya kiniun Judah

ade ori òkín

gbongbo idile Jese

aade ri òkín

aanu mo ri gba, ade ori okin

ọlọhun lo gb'ogo f'ọ́lẹ

adé ori òkín

ọlọhun lo gb'ogo f'ọ́lẹ

adé ori òkín

ki se f'eiye k'eiye

adé ori òkín

ki má de nṣe f'eiye k'eiye

adé ori òkín

ọmọ sikiru Ayinde barrister

adé ori òkín

sikiru Ayinde mo njese to ran mi oo

adé ori òkín

l'ori Ere fuji

adé ori òkín

kò De ní bajẹ ọlọrun óò

adé ori òkín

modupe ori mi

adé ori òkín

mo ma dupe ori mi

adé ori òkín

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status