Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2009

Lyrics

Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa

Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa


Leyin ogbo ojo (Serah bimo)

Leyin adorun odun (Mose goke lo)

Ina ileru (Kojo Heberu meta)

Okun pupa (Ko duro niwaju Isreli)

Igbayi nimo mope (Oluwa labo mi)

Igbayi nimo pe (Jesu lasa mi)

Alaboyun nfe (Agbara aluyo)

Omole iwe nfe (Agbara aluyo)

Gbogbo awako nfe (Agbara aluyo)

Omo ikose nfe (Agbara aluyo)


Oluwa ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa

Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa


Ohun totin fogun odun le

Were lagbe le e lowo

Oke to okole gun yo ran o lowo o

Deborah segun (Nipa agbara aluyo)

Danieli bori (Nipa agbara adura)

Mordecai bori Hamani (Orun lose)

Olorun alagbara (Koma sohun tiko le se)

Olori orile ede nfe (Agbara aluyo)

Awon minister nfe (Agbara aluyo)

Bale ile nfe (Agbara aluyo)

Jehovah (Olorun alagbara)

Ohun lagbara wa (Ati orin wa)


Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa

Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa


Oh oh Baba oh oh

Lati goke aluyo Baba ran agbara wa


(Ran agbara wa) Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa

Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa

Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa

Ran agbara wa ran agbara wa

Lati goke aluyo

Ran agbara wa

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status