Letter Of Praise Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2012
Lyrics
Baba mi toto
Iwe ope iyin mi niyin si O Iwo nimo kosi
Si O ni Alade wura
Si Oni o Olore mi
Mo dupe fun dida toda mi si tebi tara
Mo dupe pe mo si wa lona iye to fese mile o Baba
Baba mi owon
Kini ma fi fun O fun gbogbo ore Re
Kini mole fi dupe
Kani pe ounje loba magba mi o ba se delicacy to kira fun O ni Baba
Seni mba gba chef kiwon bami se ounje to special fun O ni Baba temi
Kape oko ni the latest car ni mba fi fun o
Kape ile ni mba pe awon architect ah mansion ni mba ko fun O o Baba
Kape Ole gbaso designer infact mba order fun latest fashion lati fi se O loso O Baba
Toba jepe ole gbowo ni the highest denomination hard currency ni mba ko fun o
Kape ogba gberan ni odidi malu ni mba pa fun O
Mba tun ko orisiri eranko po lati rubo ope si O Baba mi
Kini mole fi san fun O o Ololufe mi
Oba tofe mi lai nidi
Kini mole fi dupe fun O o Oba toni emi mi
Afi kin sama dupe
Kin ma yin O o fun ore Re
Ose o Ose o
Moyin O o
Omase o Baba
Nagode nagode
** Nagode
Imela imela
** Chineke imela
Thank You thank You Lord
I’m praising You
Thank You Lord
Fun anu topo bi iyanrin
Timo ngba lojumo
Latodo Jesu Oluwa
Kilemi ofifun
Emi kole sin botito
Nko ni se kan tope
Sugbon emi osogo yipe
Gbese ope mi po
Emi fe Oluwa nitori ti ogbo ohun mi ati ebe mi
Nitori tio de eti Re simi
Nitori na lemi oma kepe ni ojo mi
Ibanuje iku yimi ka
Irora iboji si
Mori iyonu ati ikaanu
Nigbana nimo kepe oruko Oluwa
Oluwa emi be O o gba okan mi
Olore ofe ati olododo ni Oluwa
Nitoto alaanu ni Olorun wa
Oluwa pa awon alaimokan mo
Aremi sile tan
Osi fi ifami ororo yan mi
Iwo okan mi nitori Oluwa se ohun opolopo fun O
Nitori ti iwo gba okan mi lowo iku
Oju mi lowo omije
Ati ese mi lowo isubu
Emi oma rin niwaju Oluwa nile alaye o
Emi gbagbo o nitorina ni emi se so wipe
Mori iponju gidigidi mori ilara pe
Eke ni gbogbo eniyan
Kini emi osan Oluwa
Nitori gbogbo ore Re simi
Emi omu ago igbala
Emi osi ma kepe oruko Oluwa
Emi oso ileri ife mi fun oluwa
Nitoto ni oju gbogbo awon
Iyebiye niku awon ayanfe Re niwaju Oluwa
Oluwa nitoto iranse Re ni emi iranse Re lemi o
Iwo titu ide mi
Emi o korin ope si O
Emi osi ma kepe oruko Oluwa
I will call on the name of the Lord
I will fulfill my vows to the Lord
In the presence of all His people
In the court of the house of the Lord
In Your new Jerusalem
Eyin Oluwa
Praise ye the Lord
Ose o Ose o
Moyin O o
Omase o Baba
Nagode nagode
** Nagode
Imela o imela 0
** Chineke imela
Thank You thank You Lord
I’m praising You
Thank You Lord
Ose o Ose o
Moyin O o
Omase o Baba
Nagode nagode
** Nagode
Imela imela
** Chineke imela
Thank You thank You Lord
I’m praising You
Thank You Lord