Ibadan (Juju Yoruba) Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1969
Lyrics
Gbogbo Ibadan e dupe o fun ile baba wa
Oluyole o e dupe o fun ile baba wa
Oke ado e dupe o fun ile baba wa
Ororo ile ororo ile
Ni baba fun wa kisu omi
Ibadan o Ibadan 2x
Ibadan ye o Ibadan
Ibadan o Ibadan
Gbogbo omo Ibadan niwon jo olorire 2x
Won ki fipa jaiye
Won komi mora
Jaiye jaiye oluyole jowo dara
Oluyole area titi tofi dorun mu 2x
Ajagbe o yewo tiwa
Oko funmilayo tiwa
Oko iyabo tiwa
Baba denrele o tiwa
Baba adewale o tiwa
Eye aluko gbewe wa wo e o
Keto fibadan sere o
Mi o ni fibadan sere o
Kato fibadan sere yi
Ife wa yonu
Keto fibadan sere o
Mi o ni fibadan sere o
Kato fibadan sere yi
Ife wa yonu
Owo yonu o owo yonu
Yi awa yonu
Aja ye opo ju wani yi awa yonu