Ijesha (Juju Yoruba) Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1969
Lyrics
Mo ki gbogbo ijesha
Omo ologi wowo ti wi wo
Omo ologi wowo ti wi wo
Ijesha ogere omo wa bokun
Mo ti ba jesha soro
Mo ti bomo wa rele
Mo ti ba jesha soro
Mo ti bomo wa rele
Ile ekun lejika o obawa
Mo ti ba jesha soro
Mo ti bomo wa rele
Mo ti ba jesha soro
Mo ti bomo wa rele
Ile ekun lejika o obawa
To ba je ti ka nawo
Won ki woju gbowo
Ka kole ka wa moto
Ijesha loni yen
Fesbi omo bakare
Pelu omole
Adajanoku ji mi gbo jigi jigi
Ewa wara tijesha fowo da
Edumare ma gba sa lowo won
Omo logi wowo tiwo beeni 2x
Nto ba fe ni awo sapo eni beeni
Eyi ti ofe ni awosinu igbo beeni
Eranko buburu a ma won mu je beeni
Obu oja wa sese woja beeni