Loading...

Download
  • Genre:Juju
  • Year of Release:1975

Lyrics

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa


Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa


Birere loba mo

Ore mi mase

Toba deje ika ole mura si

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa


Ninu oun teledumare da sile aiye

Awa eniyan lasoro

Ninu eranko teledumare da sile aiye

Amoju eran toburu

Sugbon amo omo eniyan

Tan barawa je taba barawa mu

Oun koun lole sele

Nigba kugba o abi lojowaju

Eyan mi o oro awon eniyan

Boselewu ka barawa sore to

Boselewu katu barawa sebi to

Boselewu kabarawa gbe tan

Ojulari o ore odenu yi o

Amo eran eran jekun

Keniyan je ode lai mura gidi

Ko gbodo wogbo tekun lo

Keniyan je ode lai mura gidi

Ko gbodo wogbo tekun lo

Amora awon omo eniyan

Amoju eran toburu

Amo omo eniyan

Tan barawa je taba barawa mu

Oun koun lole sele

Nigba kugba o abi lojowaju

Eran ekun eran niye ni

Kinihun olola iji eran niye ni

Eran ejo eran niye ni

Eran oya eran niye ni

Eran ogufe eran jije ni

Eran etu eran jije ni

Eran igala eran niye ni

Eran lilo logini eran oogbo

Eran lilo logini eran to ba ni sere o

Eran lilo logini eran oogbo

Eran lilo logini eran to ba ni sere o

Gbogbo alaida omu ra saida 2x

Oba u ala lejika agogo tolu meila obowa nko 2x

Toba leku siwon ti woba lejo si e

Ore mi iyen o buru

Osupa laiye ore mi

Nise laiye mi lore o

Iwa to da loye ka ma wu

Tori koseni to mojo ola

Osupa laiye ore o

Nise laiye yi lore o

Iwa to da loye ka ma wu

Tori koseni to mojo ola


Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa


Birere loba mo

Ore mi mase

Toba deje ika ole mura si

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa

Oro oluwa ede

Ye ede loro oluwa


Adura ti mogba oluwa bami muse

Nile aiye wa o kama lowo lowo

Masehun rere nile aiye mi

Apemo eni la npe temi dire

Masehun rere nile aiye mi

Ni soju ota mi o

Nile aiye mama lowo lowo

Masehun rere nile aiye mi

Lola oluwa o mama kolemole

Masehun rere nile aiye mi

Gbogbo egbe nterriformers a o sorire

Masehun rere nile aiye mi

Gbogbo egbe onilu a o sorire

Masehun rere nile aiye mi

***

Masehun rere nile aiye mi

***

Masehun rere nile aiye mi

***

Masehun rere nile aiye mi


Omumi ranti pe ilu kiwa lai solori 2x

Adeyemi alafin kabiyesi o kabiyesi o

Adeyemi oba o 2x

Adeyemi alafin kabiyesi o kabiyesi o

Adeyemi oba o

Oyo sanile alafin ebimo pe adeyemi da

Ife sanile aderemi

Oyo sanile alafin ebimo pe adeyemi da

Gbogbo omo ile ife 2x

Ema sekia ema sekia gbaderemi ga o

Ijoba aderemi lo tewa lorun

Ema sekia ema sekia gbaderemi ga o

Egba sanile molisabi

Ebimopo gbe nipede ga

Akure nile oloye mekun

Ebimopo gbe mejeji ga

Gbogbo egba eri a o 2x

Eba se kia 2x gbe nipede ga o

Ijoba nipede lotewa lorun tegba

Eba se kia 2x gbe nipede ga o


Ibadan sa nile oluyoleebimopo gbelu badan ga

Osogbo nile oloroki

Ebimopo gbe akaja ga

Ogbomoso nile ekisoun

Ebimopo gbe oyewunmi ga

Ondo nile ekinmoku

Ebimpo gbe osemowe ga

Ekiti sanile oba ewi

Ebimopo gbe egeji ga

Ijesha sanile owajaka

Ebimopo ka mu ejika ka

Gbogbo omo ilesa o

Gbogbo omo ilesa ilesao

Ema se dia 2x kamu ejika ka o

***

Ikare nile olujkare

Ebimopo gbe oloukare ga

Eko sa nile oba oyekan

Ebimopo gbe oyekan ga

Eko akete ile omo

Eko akete ile omo

Arodede ko ma maje o

Eko aromisa legbe legbe

Arodede ko ma maje o

Eko aromisa legbe legbe

Ijebu nile omo alare

Ebimopo ggbe sikiru ga

Ikare nile olukare

Ebimopo gbe olukare ga

Sikiru ayanfe sikiru oba toto

Sikiru ayanfe awujale oba toto

Odile awujale oba toto

Sikiru ayanfe awujale oba toto

Oba alafin oba oyo oba adeyemi

Sikiru ayanfe awujale oba toto

***

Sikiru ayanfe awujale oba toto

***

Sikiru ayanfe awujale oba toto

More Lyrics from Chief Commander Ebenezer Obey Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status