Loading...

Download
  • Genre:Juju
  • Year of Release:1988

Lyrics

Nitori ola se rere2x

Iwo ore mi

Nitori ola nitori ola se rere

Iwo ore mi

Nitori ola nitori ola se rere

Nitori ola se rere2x

Iwo ore mi

Nitori ola nitori ola se rere

Iwo ore mi

Nitori ola nitori ola se rere


Koseni tokogo aye da

Igba mani 2x o

Asiko ni 2x o

Iwa ni gbogbo kan

Koseni tokogo aye da

Igba mani 2x o

Asiko ni 2x o

Iwa ni gbogbo kan

Nitori ola se rere2x

Iwo ore mi

Nitori ola se rere

Iwo ore mi

Nitori ola nitori ola se rere


Imole ti de

Okunkun parada

Imole ti de

Okunkun parada

Parada 3x

Imole ti de

Okunkun parada

Imole ti de

Okunkun parada

Parada 3x


Yo ro yo ro

Ojo ibukun yoro

Yo ro yo ro

Ojo ibukun yoro

Iba je lero loni

Ibukun owo pelu omo

Iba je lero loni

Ibukun owo pelu omo

Yo ro yo ro

Ojo ibukun yoro

Yo ro yo ro

Ojo ibukun yoro

Iba je lero loni

Ibukun owo pelu omo


Olusegun o olusegun o

Omo osoba omo osoba akinrougun obawode

Olusegun o olusegun o

Omo osoba omo osoba akinrougun obawode

Olusegun o olusegun o

Omo osoba omo osoba akinrougun obawode

Olusegun o olusegun o

Omo osoba omo osoba akinrougun obawode


Igbati won bi segun

Omo osoba

Osa ni olusegun aja segun

Ojojumo lo segun

Oun segun lojojumo

Chief olusegun omo osoba yi

Oko olukemi oba olumide

Baba oluyinka baba olu adobi

Nigbati won bi segun omo osoba

Osa ni olusegun aja segun

Ojojumo lo segun

Oun segun lojojumo

Kabiyesi o oba oba onipede

Omo e nijogun ola

Tofi olusegun jaki rock o

kabiyesi o oba oba onipede

Omo e nijogun ola

Tofi olusegun jaki rock o

Igba ti segun ti joye

Won fi je akin robu

Ojojumo loun segun

Oun segun lojojumo

Tafi na toye coker ese adupe

Balogun sanya olu

Chief obakun omo abiola

Doctor rasheed aderite

Toye toye rite

Afona olufunke

Ati chief adeboye

Ese adupe

***

Omo eni sebo mefa loba

Ofemo ofeya ofagadamo

***

Tapa tapa 2x

Osoba yi daraba olusegun

Tapa tapa 2x

Osoba yi daraba olusegun

Ore felix adenaike

Ore peter ajayi

Ore sam aputa

Awo sunny kuku ni jebu de

Olorogun nijebu ode

Sunny kuku nijebu ode

Awofunlola ogunnawo

Awobukola ohuntowomi

***

Abatapa abatapa oloba yi

Daraba olusegun

Abatapa abatapa oloba yi

Daraba olusegun


Sunny kuku oko rita

Oorogun nijebu ode

Baba olubanke baba foluso

Ye olu baba folarin

Omo kuku nijebu ode

Omo kuku nijebu ode

Irawo eledumare logbelayelowa

Omo kuku nijebu ode

Aiye wa toro 3x

Oluwa bafe

Aiye wa toro 3x

Oluwa bafe


Adetola oba nijebu toto oba

Awojeje oba nijebu toto oba

Adetola oba nijebu toto oba

Awojeje oba nijebu toto oba

***

More Lyrics from Chief Commander Ebenezer Obey Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status